THE SEED
And Jesus said to them, I am the bread of life. He who comes to Me shall never hunger and he who believes in Me shall never thirst. John 6:35
Bread is a widely popular food in all culture and society. From the north to the south and from the west to the east, it is a very common food. Food serves various purposes for humans. The most important reason we eat food is to sustain life and to bring about growth and development in our body systems. Jesus Christ made a very bold statement in the scripture stated above, ‘I am the bread of life’. Nobody else has made such a statement before except Almighty God. When you come to Jesus Christ and accept Him as your Lord and Saviour, all the voids in your life shall be filled. There will be first an inner satisfaction. You will thirst and hunger no more.
PRAYER
May I be satisfied by the bread of life in Jesus name, Amen
BIBLE READINGS: John 6:30-37.
OUNJE IYE
IRUGBIN NAA
Jesu wí fún wọn pé, “Èmi ni oúnjẹ ìyè: ẹnikẹ́ni tí ó bá tọ̀ mí wá, ebi kì yóò pa á; ẹni tí ó bá sì gbà mí gbọ́, òǹgbẹ kì yóò gbẹ ẹ́ mọ́ láé. Johanu 6:35
“Jesu wí fún wọn pé, “Èmi ni oúnjẹ ìyè: ẹnikẹ́ni tí ó bá tọ̀ mí wá, ebi kì yóò pa á; ẹni tí ó bá sì gbà mí gbọ́, òǹgbẹ kì yóò gbẹ ẹ́ mọ́ láé” Johannu 6:35. Akara je ounje ti ó wopo ni opolopo awujo ati asa. Orisirisi si ni ise ti ounje n se ninu aye eniyan. Idi pataki ti a fi maa n je ounje ni lati gbe emi ro ati lati mu idagbasoke ba ago ara. Jesu Kristi so ninu Iwe Mimo wipe “Emi ni ounje iye”. Ko si eniyan to so iru oro yii ri bikose Olorun Alagbara. Nigba ti o ba to Jesu Kristi wa, ti o si gba gege bii Oluwa ati Olugbala re, gbogbo ofo ni a o bawi kuro ninu aye re. Ni akọkọ, iwo yio yo. Iwo ki yio si p’ebi tabi p’oungbe mo lailai.
ADURA
Jeki ounje iye temi lorun, ni oruko Jesu, Amin
BIBELI KIKA: Johannu 6:30-37