THE COMING BACK OF JESUS

THE SEED

“Look, he is coming with the clouds,” and “every eye will see him, even those who pierced him”; and all peoples on earth “will mourn because of him.” So shall it be! Amen.” Revelation 1:7 NIV

Jesus is coming back to take His beloved ones home. When He comes what will He meet you doing? He already came to the world to die for our sins and cleanse us from all unrighteousness so that we may be able to stand before the throne of grace and obtain mercy in times of need. We are like fruits planted in the garden that should yield its fruits in its season and when the gardener comes to pack all the fruits he will throw away the bad ones and pack the good ones in His barn. The Angels told His disciples that all eyes shall see Jesus in His return, the same way He ascended to heaven to take the righteous home. How prepared are you to meet with your Lord and Saviour? The only preparation is to live your life daily like He is coming today and remember nothing unholy can enter into the kingdom of God. We will all appear before the judgement throne and receive the reward for everything we have done on earth, so, let’s endeavour to be in alignment with God and walk with Him daily. Jesus’ coming will be like a thief in the night, nobody knows the exact time it will be but everyone will receive their judgement immediately after death. It’s going to be everybody’s judgement day. The signs He told us to look out for are happening already, be prepared for the second coming of Jesus Christ.

BIBLE READING: Rev 1:4-8

PRAYER: Oh Lord, Help me to ascend with you when you come and take your loved ones home, Amen.

 

IPADABỌ JESU

IRUGBIN NAA

“Kíyèsí i o nbọ ninu àwọ̀sanma; gbogbo ojú ní yíò ri i, ati awọn ti o gun un lí ọ̀kọ pẹ̀lú; àti gbogbo orilẹ-ede aiye ni yió sí máà pohùn réré ẹkún níwájú rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ náà ni Àmín”. ÌFIHÀN 1:7.

Jésù ń bọ̀ wá kó àwọn èniyàn rẹ̀ lọ sí lé. Nígbà tí ó bá dé, kí ni yíò ba ọ pé oun ṣe? Ó ti wa si aiye lati ku fun ẹṣẹ wa lati wẹ wa mọ kuro ninu àìṣòdodo ki a ba a le duro niwaju itẹ Ore-ọfẹ, ki a si ri aanu gba ni awọn akoko ti à nílo aanu. A dabi awọn eso ti a gbin sinu ọgba tí o yẹ ki o so èso rẹ̀ ní àsìkò rẹ̀ àti nígbà tí olùṣọ́gbà bá dé láti ko gbogbo èso jọ, yíò sọ èyí tí ó bájẹ danù, yíò sì kó àwọn èyí tí ó dára jọ sínú abà rẹ̀. Àwọn áńgẹ́lì náà sọ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé gbogbo ojú ni yóò rí Jesu nínú ìpadàbọ̀ Rẹ̀, bákan náà ni Yíò ṣé gòkè re Ọ̀run láti kó olódodo lọ sí lé. Bawo ni o ṣe mura lati pade pẹlu Oluwa ati Olugbala? Igbaradi kan ṣoṣo ti o ni, ni lati gbe Igbesi aye Rẹ lojoojumọ bi ẹni pe O ti nbọ loni; ki o ranti ohunkohun ti o jẹ́ alaimọ ki yio le wọ ijọba Ọlọrun. Gbogbo wa ni a o fara han niwaju itẹ idajọ lati gba ere fun ohun gbogbo ti a ti ṣe lori ilẹ aiye, nitorina, jẹ ki a gbiyanju lati wa ni ibamu pẹlu Ọlọrun ati ki a rin pẹlu Rẹ lojoojumọ. Wiwa Jesu yio dabi ole ni oru, ko si ẹnikan ti o mọ akoko gangan ti yio jẹ, ṣugbọn gbogbo eniyan ni yio gba idajọ wọn lẹsẹkẹsẹ lẹhin ikú. Yíò jẹ ọjọ idajọ gbogbo eniyan. Àwọn àmìn tí Ó sọ pé kí a máa wo ọ̀nà fún ti ńṣẹlẹ̀ lọwọ lọwọ, múra sílẹ̀ de ìpadàbọ̀ Jésù Kristi.

BIBELI KIKA: Ìfihàn 1: 4-8.

ADURA: Oluwa, Ran mi lọwọ lati ba Ọ goke nigba ti O ba wa mu àwọn ayanfẹ Rẹ lọ sile. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *