THE SEED
“But when He saw the multitudes, He was moved with compassion for them, because they were weary and scattered, like sheep having no shepherd.” Matthew 9:36
A compassionate person is merciful and not only are they concerned about those that are going through tough times and facing challenges but they also do something about the situation and help the person out of the problem. Our Lord Jesus Christ is a compassionate One. He loves everyone even if you haven’t given your life to Him, He can be ready to help. Some people help because they can help, some because they want to be famous and some don’t mind if they cause further harm while trying to help, all these without compassion is just show-off. Even if you are gifted with many spiritual gifts and you are not compassionate, it may not be acceptable in the sight of God and it may all amount to nothing meaningful. Follow the example of the only Son of God. Be loving and compassionate to others.
PRAYER
Lord help me to be filled with compassion in my dealings with others in Jesus’ name. Amen.
BIBLE READINGS: Isaiah 54:10-12
ALAANU NAA
IRUGBIN NAA
“Ṣùgbon nígbà tí ó rí opolọpo ènìyàn, àánú wọn ṣe é, nítorí tí ó re won, won sì fonká, bí àwọn àgùntàn tí kò ní olùṣo.” Mátíù 9:36
Èèyàn oníyonú je aláàánú, kì í sì í ṣe wipe aanu awon ti o n la isoro koja nikan maa n se won ṣùgbon won maa gbe igbese lati ranwo lowo kuro ninu isoro won. Oluwa wa Jesu Kristi jẹ Ẹni alaanu. O nifẹ gbogbo eniyan botile je wipe, Iwo ko ti Fi aye re fun. O setan lati ṣe iranlọwọ. Diẹ ninu awọn eniyan ṣe iranlọwọ nitori pe wọn le ṣe iranlọwọ. Diẹ ninu wọna maa ran ènìyàn owo nitori wọn fẹ lati jẹ olokiki. Awon miran ko si bikita wipe iranlowo won tun le mu isoro dani. Sise gbogbo nkan wonyí laisi aanu, se Kari mi lasan ni won je. Ti o ba ni ẹbun emi ti o Po, ti o si je alailanu, ko le je itewogba niwaju Ólorun, gbogbo awon ẹbun na síle je asan. Tẹle apẹẹrẹ Ọmọlorun kanṣoṣo,ma fife han ki o si maa saanu fun awọn ẹlomiran.
ADURA
Oluwa ran mi lowo lati kun fun aanu ninu ibalo mi pelu awon elomiran ni oruko Jesu. Amin.
BIBELI KIKA: Aísáyà 54:10-12