The Danger Of A Hardening Heart

THE SEED
Do not harden your hearts, as at Meribah, As in the day of Massah in the wilderness, Psalm 95:8

Many people battle with a hardened or indifferent heart, yet there is a cure: noticing God at work and giving Him thanks. When Israel arrived at Rephidim (Exodus 17) and bemoaned the scarcity of water, this prescription for a soft heart was disregarded. They had recently witnessed the manna miracle, which served as a reassuring reminder that God was with them. But a few days later, people began to question whether the Lord was present. Exodus 17:7. They could have re-established their faith in God and held out hope for a water supply by thanking God for His provision through the manna experience and remember His goodness. Another time, Pharaoh ignored the obvious when God commanded Moses to speak to him. Even his own magicians confessed God’s handiwork, and declared, “This is the finger of God” (Exodus 8:19), but Pharaoh remained hard-heartened until he met his waterloo. A hardened heart cannot heed the instruction of God. Consider the condition of your heart today, then follow the Holy Spirit’s leading.

PRAYER
Father Lord, let not my heart be hardened unto destruction
BIBLE READINGS:  Psalm 95:1-11

EWU TI N BẸ NINU SÍSÉ OKAN LE

IRUGBIN NAA
Ẹ má e sé ọkàn yín le gẹ́gẹ́ bí ẹ ti e ní Meriba, àti bí ẹ ti e ní ọjọ́ náà ní Massa ní aginjù. Orin Dafidi 95:8

Ọpọlọpọ wa ni a máa n jijakadi pelu agidi okan. Ona abayọ fun eyi ni lati mọ̀ nigba ti Oluwa ba n ṣisẹ́ ki a si fi ọpẹ fun. Nigbati awọn ọmọ Isreli de Rẹfidimu ninu iwe Ẹksodu 17 ti woṇ ko si ni omi lati mu, won kọ̀ lati tele ona abayo yii. E ranti wipe laipẹ ni won ri iyanu manna, eyi ti o je idaniloju wipe Oluwa n bẹ pẹlu won. Sugbon lehin ọjọ melo kan, won bẹrẹ sinni siyèméjì boya lootọ́ ni Oluwa wa pẹlu won. (Eksodu 17:7). Won i ba fi igbagbọ won mulẹ ki won si ni ireti fun ipese nipa fifi ọpẹ fun Oluwa fun iriri manna ki won si ranti ore rẹ̀. Àpẹẹrẹ miran ni Farao, ti o kọ̀ lati gbọ́ nigbati Olorun paṣẹ fun Mose lati baa wi. Botilẹ jẹ wipe awon onídán rẹ jewo wipe ”ìka Olorun ni eyi” (Eksodu 8:19), Farao se aya re le titi ti o fi parun. Ọlọkan lile ko le gbo àṣẹ Oluwa. Yẹ okan rẹ wo loni ki o si gba itona Ẹmi Mimọ.

ADURA
Oluwa, maṣe je ki n se ọkan mi le fun iparun. Amin.
BIBELI KIKA: Orin Dafidi 95:1-11

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *