The Humble

THE SEED
“Therefore whoever humbles himself as this little child is the greatest in the kingdom of heaven.” Matthew 18:4

Society only expects the poor, less privileged, the illiterate and people that have challenges to be humble. They expect rich and famous people to be proud. This is not so in the Kingdom of God. Jesus said in the above scripture that all men should humble themselves just like the way children are usually humble. You have to discipline yourself and be humble. A situation may arise that want to test if you are humble like the Saviour you profess to be following who was so humble that he left His deity to put on the nature of man, He was given birth in a manger, HE walked on earth and went through persecution, suffered and died for all humanity on the cross of Calvary so that He can take away our sins. Humble yourselves therefore under the mighty hand of God, that he may exalt you in due time. 1 Peter 5:6. Being humble does not mean you are sluggish or not smart.

PRAYER
I receive the grace to be humble indeed in Jesus’ name. Amen.
BIBLE READINGS:  1 Corinthians 1:26-30

   ONIRELE

IRUGBIN NAA
“Nítorí náà ẹnikẹ́ni tí ó bá rẹ ara re síle gẹ́gẹ́ bí ọmọ kékeré yìí ni ó tóbi jùlọ ní ìjọba orun.” Mátíù 18:4

Awujo lo n ma n ro wipe, awon alaini,alainiranlowo,eniti ko kawe ati awon ti o ni idojuko nikan logbudo je onirele. Wọn nireti pe awọn ọlọrọ ati olokiki eniyan lati gberaga. Èyí kò rí bẹ́ẹ̀ nínú Ìjọba Ọlọ́run. Jésù sọ nínú ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tó wà lókè pé gbogbo èèyàn ló yẹ kó rẹ ara wọn síle gẹ́gẹ́ bí àwọn ọmọdé ṣe máa ń jẹ́ onírele. O ni lati ṣe ibawi ararẹ ki o jẹ onirẹlẹ. Isele miran le selẹ lati dan o wo bo ya o jẹ onirẹlẹ gege bi Olugbala ti Iwo so wipe Iwo n tele. Eniti o je onirele Debi pe, o Fi ogo re síle láti gbe eyà ènìyan wo. A bi i so ibujẹ ẹran, O rin lori ilẹ a si se inunibini si I, o  jiya o si ku fun gbogbo eda eniyan lori agbelebu ti Kalfari ki o le mu ese wa kuro. Nítorí náà ẹ rẹ ara yín síle lábẹ́ ọwọ́ agbára Ọlọrun, kí ó lè gbé yín ga ní àkókò ti o yẹ. 1 Pétérù 5:6 . Jije onirẹlẹ ko tumọ si pe o ko jafafa.

ADURA
Mo gba oore-ọfẹ lati jẹ onirẹlẹ nitõtọ ni orukọ Jesu. Amin.
BIBELI KIKA: 1 Kọ́ríńtì 1:26-30

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *