THE JOY THAT NEVER BREAKS

THE JOY THAT NEVER BREAKS

THE SEED

“When anxiety was great within me, your consolation brought me joy.” — Psalm 94:19 (NIV)

As children of God, our joy is not determined by circumstances but by the presence of God in us. While the world is full of anxiety and uncertainty, God remains our unshakable source of strength and joy. His presence calms storms and sustains our hearts. It’s natural to feel anxious at times, but we must not let anxiety settle or steal our joy. Divine joy is strength—it lifts, sustains, and stabilises the believer even in tough seasons. The enemy often targets joy because he knows its power. But when we remain close to Jesus, the source of joy, our strength stays unbroken.

Reflection: Joy in God is stronger than the pressures of life.

 

BIBLE READING: Habakkuk 3:17–19

PRAYER: Father, let Your divine joy continue to be my strength every day of my life. Amen.

 

AYỌ̀ TÍ KÒ NÍ ÌDÁDÚRO

IRUGBIN NAA:

“Nígbà tí àníyàn ńlá wà nínú mi, ìtùnú rẹ̀ mú ayọ̀ sí ọkàn mi.” — Sáàmù 94:19

Ayọ̀ wa gẹ́gẹ́ bí ọmọ Ọlọ́run kì í ṣe nipa awon ìsẹ̀lẹ̀, bikose nipa ìwàláàyè Ọlọ́run nínú wa. Nígbà tí ayé bá kún fún àníyàn àti àìdánilójú, Ọlọ́run ni orísun agbára àti ayọ̀ wa. ìwàláàyè Re n mu ki iji dákẹ́jẹ́, ti o si n gbe okan wa ró. Ó jẹ́ ohun àbùdá ènìyàn láti ṣàníyàn nígbà míì, ṣùgbọ́n a kò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí àníyàn jí ayọ̀ wa. Ayọ̀ àtọ̀runwá jẹ́ agbára; ó ń gbé wa ró, ó sì ń jẹ́ kí onígbàgbọ́ dúró ṣinṣin ní àkókò líle. Ota maa n dojuko ayọ̀ wa nitori wipe ó mo agbara rẹ̀. Nígbà tí a bá sún mọ́ Jésù, orísun ayọ̀, agbára wa kì yóò rẹ̀.

ÀṢÀRÒ: Ayọ̀ nínú Ọlọ́run lágbára ju ìdààmú ayé lọ.

 

BIBELI KIKA: Hábákúkù 3:17–19

ADURA: Baba, jẹ́ kí ayọ̀ Rẹ̀ àtọ̀runwá jẹ́ agbára fun mi lójoojúmọ́. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *