The Lord’s Classroom

THE SEED
“He instructs sinners in his ways.” Psalm 25:8

“Good and upright is the LORD; therefore he instructs _______ in his ways.” What might fill in the blank? “The righteous” would fill the blank nicely. The righteous are so teachable. They listen to the instructor and do as they are told. But the psalmist says, “He instructs sinners in his ways.” Sinners? The Lord must specialize in difficult students. Actually, this teaching is very encouraging. We are all sinners, so we are all welcome in the Lord’s classroom. Let’s take a look at our class schedules. What? No electives? No vacations? Classes meet 24 hours a day, 7 days a week, 365 days a year? What’s more, if we skip class, the Lord comes looking for us! And when we don’t get the assignment right, we must do it over till we get it right! Actually, none of us gets a perfect score. As sinners, we can never be perfect. But God counts us righteous because of Christ, who gave his perfect life for us. That keeps us humble. “He guides the humble in what is right and teaches them his way.” And when we do stray into pride, we can pray, “Forgive my iniquity, though it is great.”

BIBLE READING: PSALM 25

PRAYER: Lord, we thank you for teaching us your ways, especially in and through the work of Jesus, in whose name we hope. Amen.

YARA IKEKO OLUWA

IRUGBIN NAA
“Ó ń ko àwọn ẹleṣẹ̀ ní ọ̀nà rẹ̀.” Iwe Orin Dafidi 25:8

“Rere ati iduroṣinṣin ni Oluwa; nítorí náà ó ń to ní _____ ni onà rẹ̀.” Kini a le Fi di alafo naa? “Olódodo” yóò di alafo náà dáradára. Awon olódodo rorun Lati ko. Won máa ń tetí sí olùko, won sì ń ṣe bí won ṣe sọ fún wọn. Ṣùgbon onísáàmù náà sọ pé, “Ó ń ko àwọn ẹleṣẹ̀ ní ọ̀nà rẹ̀.” Awọn ẹlẹṣẹ? Oluwa gbọdọ farabale ko awon ọmọ ile-iwe ti o le Lati ko. Eko yi n gba eniyan niyanju. Gbogbo wa jẹ ẹlẹṣẹ, nitorinaa gbogbo wa ni a tewogbà ni yara ikeko Oluwa. Jẹ ki a wo awọn eto iṣe kilasi wa. Ki leyi? Ko si asiko isinmi? Ojoojumo ni ikeko wa titi de opin odun. Ti a ba pa eko je, Ọlorun yio maa wa wa Kiri. Ti a ko ba si se ise amurele wa daradara, a gbudọ tunse titi ti yio Fi se itewogba. Lootọ, ko si ọkan ninu wa ti o le gba ise ni pipe. Gege bí ẹleṣẹ̀, a kò lè je pípé láé. Ṣùgbon Ọlorun kà wá sí olódodo nítorí Kristi, ẹni tí ó fi ẹ̀mí rẹ̀ pípé lélẹ̀ fún wa. Iyẹn jẹ ki a jẹ onirẹlẹ. “Ó ń ṣamọ̀nà àwọn onírẹ̀lẹ̀ nínú ohun tí ó to, ó sì ń ko wọn ní ọ̀nà rẹ̀.” Àti pé nígbà tí a bá ṣáko lọ sínú ìgbéraga, a lè gbàdúrà wipe, “Dárí ẹ̀ṣẹ̀ mi jì, bí ó tilẹ̀ je pé ó pọ̀.”

BIBELI KIKA: Sáàmù 25

ADURA: Oluwa, a dupẹ lọwọ rẹ fun kikọ wa ni awọn ọna rẹ, paapaa ninu ati nipasẹ iṣẹ Jesu, ninu orukọ ẹniti a nireti. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *