THE SEED
“Wisdom is the principal thing: therefore get wisdom: and with all thy getting get understanding” Proverbs 4:7 KJV
As a child of God in order to have the best in life, it is necessary to get your priorities right if you don’t want to mess up. Godly wisdom, according to Proverbs 4, is the principal thing. This means wisdom is the most important thing. Life without wisdom will be full of struggles and stress. Solomon understood how important wisdom is, when God gave him a blank check to fill, he quickly chose Wisdom. He should have chosen riches and wealth, but he knew that wisdom will eventually lead to riches and wealth. Dearly beloved, do you know that the very solution to every life situation is located in wisdom. Wisdom root will produce every good fruit you need in life. But you need to be committed to developing a good relationship with God and His word.
BIBLE READING: Proverbs 4: 5-11
PRAYER: Oh Lord God, Give me the wisdom to live my life in Jesus Mighty Name Amen.
OHUN TI O SE PATAKI JULO
IRUGBIN NAA
“Ipilese ohun gbogbo ni ogbon, ati pelu ini re gbogbo, ni oye.” Owe 4:7
Gege bi omo Olorun, lati le se rere laye, o ni lati mo ohun ti o se pataki fun aye re bi o ko ba fe se asise. Ogbon Olorun, gege bi Owe 4, ni ipilese ogbon. Eyi tumo si wipe, ogbon je ohun ti o se koko julo. Igbe aye eni ti ko ni ogbon yio kun fun idamu ati whala. Solomoni mo bi ogbon ti se pataki to, nigbati Olorun bere ohun ti o fe lowo re, o yara mu ogbon. Ohun iba ti mu oro ati ola, sugbon o mo wipe ogbon yio so ohun di olola ati oloro. Olufe owon, nje e mo wipe ona abayo si oniruuru isoro mbe ninu ogbon, gbongbo ogbon a maa so gbogbo eso rere ti o nilo laye sugbon o nilo lati faraji ki o si ni ibasepo ti o dara pelu Olorun ati Oro re.
BIBELI KIKA: Owe 4:5-11
ADURA: Oluwa, Olorun, fun mi ni ogbon lati gbe igbe aye mi ni oruko Jesu ti o lagbara. Amin