THE SEED
“In everything give thanks; for this is the will of God in Christ Jesus for you.” – 1 Thessalonians 5:18 (NKJV)
Gratitude is a powerful spiritual key. It shifts our focus from problems to God’s faithfulness. It unlocks joy, peace, and divine intervention. Paul instructs us to give thanks in everything— not because everything feels good, but because God remains good. When Jesus gave thanks with just five loaves and two fish, multiplication happened. When Paul and Silas gave thanks in prison, chains broke. A grateful heart sees beyond the present. Thanksgiving confuses the enemy and honours God. Let gratitude be your daily language, no matter the season.
BIBLE READINGS: Philippians 4:4–7 (KJV)
PRAYER: Father, give me a grateful heart that continually exalts You above every circumstance. Amen.
AGBÁRA ÌDÚPÉ ̣
IRUGBIN NAA
Ẹ máa dúpẹ́ nígbà gbogbo nínú ipòkípò tí o wù kí ẹ wà; nítorí pé, èyí ni ìfẹ́ Ọlọ́run fún yin nínú Kristi Jesu nítòótọ́ . Tesalonika 5:18
Idupe je koḳ oṛ o ̣ti emi ti o lágbára. O maa n ́́́ mu oju wa kuro ni isoro wa lo si ododo Olorun. O maa n sị́ ayo, alaafia ati idasi atokewa. Paulu gba wa ni imoran lati dupe ninu ohun gbogbo; kiise nitori pe ohun gbogbo dara sugbon nitori pe Olórun dara sibe. Nigba ti Jésù dúpé pelu Osu akara marun un àti eja meji, o di opo. Nigba ti Paulu ati Sila dúpé logba ewon, sẹ ́ḳ éseḳ è ̣ wonja! Okan ope máa nri ko ja ohun to n sele lowo lowo. Ope maa n da imo ota ru, o si maa n bu ola fun Olorun. Je ki ope je ede re lojoojumo, bo ti wu ki igba naa ri.
BIBELI KIKA: Filipi 4:4-7
ADURA: Oluwa, fun mi ni okan ope ti yio maa gbe O ga ju gbogbo ipo lo. Amin.