THE SEED
“Death and life are in the power of the tongue: and they that love it shall eat the fruit thereof.” – Proverbs 18:21 (KJV)
Words carry spiritual power. Sister Blessing reversed evil declarations spoken against her by boldly confessing God’s Word — and God honoured her faith. As believers, we must not be passive when negative words are spoken against us. Our confession of faith silences the enemy. Speak life into your destiny, family, health, and future. A closed mouth is a closed destiny.
BIBLE READINGS: James 3:1–12 (KJV)
PRAYER: Father, in Jesus’ name, I cancel every evil word spoken against my destiny. I speak life, victory, and blessings into my future. Amen.
AGBARA AHON
IRUGBIN NAA
Ikú ati ìye mbẹ ni ipa ahọn: awọn ẹniti o ba si nlò o yio jẹ ère rẹ̀. Owe 18:21
Agbara emi wa ninu oro. Arabirin Blessing da oro ibi ti a ti so sii pada , nipa siso oro Olorun, Olorun si fi ola fun igbagbo re. gege bi onigbagbo, ao gbudo dake nigba ti won ba soro odi siwa. Ijewo igbagbo wa yio mu ota dake . so iye sinu ayanmo re, ebi re, ilera re ati ojo iwaju re. enu ti o pade ni ayanmo tio pade
BIBELI KIKA: Jakobu 3:1-12
ADURA: Baba, ni oruko Jesu, mo fagi le gbogbo oro ibi ti won so lodi si ayanmo mi. mo so ti iye, isegun ati Ibukun si ojo ola mi Amen.