THE REWARD OF FAITHFULNESS

THE SEED
“His master replied, ‘Well done, good and faithful servant! You have been faithful with a few things; I will put you in charge of many things. Come and share your master’s happiness!” Matthew 25:21(NIV)

Faithfulness is a quality that God greatly values. It is the steady, unwavering commitment to honour Him, even in the small, unseen tasks. In the parable of the talents, the servants who invested wisely were not only rewarded with more responsibility but also invited into their master’s joy. God’s measure of success is not always in the grand, public achievements but in the quiet, consistent acts of obedience. Faithfulness in small things prepares us for greater assignments and opens the door to divine favour. Today, remember that every small act of faithfulness counts. God sees, He remembers, and He rewards.

BIBLE READING: Luke 16:10-12
PRAYER: Lord, help me to be faithful in the small things. Let my life be marked by steady obedience and unwavering commitment to Your will in Jesus’ name, Amen.

ÈRÈ JÍJẸ OLOTITỌ IRUGBIN NAA
“Oluwa rẹ̀ wí fún pé, o ṣeun, ìwọ ọmọ ọ̀dọ̀ réré àti olootọ: Ìwọ ṣe olootọ nínú ohun diẹ, èmi o mú ọ ṣe olórí ohùn púpọ̀: ìwọ bọ́ sínú ayọ̀ Oluwa rẹ” Mátíù 25:21

Ìṣòtítọ́ jẹ́ ohun pàtàkì tí Ọlọ́run mọ riri rẹ̀ gidi. O duro ṣinṣin, ìfaraji ti ko lé mi lati bu ọla fun un, paapaa ninu awọn iṣẹ kékeré ṣiṣe, ti a ko ri. Nínú òwe àwọn tálẹ́ńtì náà, àwọn ìránṣẹ́ tí wọ́n fi ọgbọ́n lo owó wọ́n, lẹ́yìn náà wọ́n ko san èrè iṣe réré fún wọn nikan , ṣùgbọ́n wọ́n tún pè wọ́n sínú ayọ̀ Ọ̀gá wọn. Òṣùwọ̀n ti Ọlọrun fi nwọn aṣeyọri ki i ṣé àṣe hàn ita gbangba, ṣugbọn ni idakẹjẹ, awọn iṣe igbọran deede. Ijolotitọ nínú àwọn ohun kékeré n pèsè wa fún iṣẹ́ ńlá àti ilẹ̀kùn ti o ṣi silẹ fun ojúrere àtokewá. Loni, ranti pe gbogbo iṣe kekere nipa ṣíṣe otitọ ṣe pataki. Olorun ri i, O ranti, O si nsan ẹsan.

BIBELI KIKA: Lúùkù 16:10-12
ADURA: Olúwa ràn mí lọwọ lati jẹ́ olotitọ nínú àwọn ohun kékeré. Jẹ́kí a fi àmì ìgbọràn sinú ayé mi atí ìfaraji tí kó ní iyèméjì sí ìfẹ́ Rẹ ni orúkọ Jesu Àmín.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *