The Story Of Jesus

Jesus Face Rostro Jesús Santa Faz

THE SEED
“He was in the world, and the world was made by him, and the world knew him not.” John 1:10

The story of Jesus. The world needs to hear and understand that Jesus is just as relevant today as He was then. The world needs to hear the story that without Jesus there is no “Joy to the World.” You can out-law open crusade to demonstrate the power of God in the desert and other parts of the world, but it’s going to be about Jesus. Without Jesus there is no Peace on earth or goodwill toward men. Without Jesus there are no “Silent night, Holy nights.” Even in the darkness of that tomb, over in the direst of situations, the most hopeless of circumstances, the Light shined and the darkness could not stop it. Somebody needs to tell this world that He’s the greatest Gift ever given to mankind. In a world of selfishness, He teaches us how to be selfless. In a world of hate, He teaches us how to love. In a world of no forgiveness, He teaches us how to forgive. In a world of hopelessness, He teaches us how to have hope. But more than all that, He does what no one else can do, He washes away our sins, broke the bonds of death and set the captives free. Dearly beloved, who’s going to know these things if the story isn’t told by you and me.

PRAYER
Lord Jesus give me the grace to know you more in Jesus name Amen.

BIBLE READINGS: Luke 7: 18-23

ÌTÀN JÉSÙ
IRÚGBÌN NÁÀ
“On sí wà li ayé, nipasẹ rẹ li a sì ti dá ayé, ayé kó sí mọ ọ.” Johannu 1:10

Ìtàn Jesu, Gbogbo ayé ni lati gbọ ati lati ni òye pé, Jésù sí ṣe pàtàkì sibẹ gẹgẹ bí o ti ṣe wà ní ìgbà kan rí. Ayé níláti gbọ ìtàn pé lai sí Jesu kò lè sí ayọ ni ayé. A lè ṣe isọji ita gbangba lati ṣe afihan agbara Ọlọrun ní aṣálẹ̀ ati ni ọpọ ibí gbogbo ninu ayé; ṣùgbọ́ n ohun gbogbo nilati jẹ nipa Jesu. La i sí Jésù ko le sí ayọ ni ayé tabi ìfẹ inú rere sí eniyan. La i sí Jésù kò lè sí “Òru idakẹ rọrọ, Òru Mimọ” Ninu ibojì ti o ṣokunkun, lórí iṣẹlẹ ti o ní ẹrú, ayidayida tí kó nireti, imọlẹ tán, okuku kò sí lè dá dúró. Ẹnikan nilo lati sọ fún aráyé pe Jesu ní Ọrẹ ti o tóbi julọ ti a fí fún aráyé. Ninu ayé ìmọ tara ẹni nìkan, O kọ́ wa ki a máa ṣe dara dara sí ẹni keji wá, la iboju wẹhin. Ninu ayé tí ikorira wa, O kọ wa ki a ní ìfẹ. Nínú ayé tí kò sí Idariji, O kọ wa láti d’áríjì ará wà. Nínú
ayé alainireti, O kọ́ wa láti ní ìrètí. Sugbọn jù gbogbo rẹ lọ, O ṣe ohun tí ẹnikẹ́ni kò lèe ṣe. O wẹ ẹṣẹ wá nu, O já ide ikú, o tu ondè silẹ. Olufẹ ọwọn, ta ní o fẹ mọ awọn nkan wonyi, ti kò bá sí tí ìtàn tí a sọ fún iwọ ati emi.

ADURA
Oluwa wa Jesu Kristi fún mí ní ore-ọfẹ lati mọ ọ síi ní orúkọ Jésù Àmín.

BIBELI KIKA: Luku 7: 18-23

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *