The Treasures

THE SEED:
“Lay not up for yourselves treasures upon earth, where moth and rust doth corrupt, and where thieves break through and steal” Matthew 6:19

Jesus Christ, our Lord and Savior, is so kind to make clear to us two locations where treasures are kept: on Earth and in heaven. There are several qualities about these two locations that are noteworthy. There are limitations to keeping valuables on Earth because moth and rust there could ruin them and even thieves could gain access to the treasures and take them. Heaven, on the other hand, is an unlimited storage facility for valuables; neither rust nor moth can ruin them, nor can robbers break in and take them. What one individual may consider to be a treasure, another individual may not. Therefore, everything our heart desires and requires our full focus and attention can be viewed as a treasure. The message of our Lord Jesus Christ is held in the highest regard by God. As a result, individuals whose hearts beat for the gospel and who give it their full attention and quality of time are storing up treasures in heaven. Furthermore, people who support the gospel are storing up wealth in paradise. Believers, the location of your treasures indicates the state of your heart.

Bible Reading: Matthew 6:15-20
PRAYER:
I surrender all and cling to source of true treasures in Jesus name.

FIFUNNI JẸ ÌSÌN
IRUGBIN NAA:
“Nigbati nwon sí wọ Ile nwọn ri ọmọ ọwọ naa pẹlu Maria iya rẹ, nwọn wolẹ, nwọn sí foribalẹ fún u: nigbati nwọn sí tu ìṣura wọn, nwọn tá a lọrẹ wura, ati turari, ati òjíá.” Matiu 2:11

Nigbati awọn amòye ri Jesu,wọn ni iyanu nla. Wọn wolẹ lori eekun wọn lati juba rẹ pẹlu ohun gbogbo ti wọn ni. Fifunni jẹ ìṣe ti a la kalẹ. Wọn nilo lati kẹ ẹ pẹlu ìfẹ àti àwọn ẹbùn. Wọn fifunni nitori pe wọn jẹ ọlọpẹ, wọn sí nilo lati bù ọlá fún ùn. Nigbati o bá fifun Ọlọrun, kò fẹ kí o ṣe bẹẹ nitori pe o jẹ àsìkò ọrẹ tàbí o lero pe o wun ọ lati ṣe bẹẹ. Bíbélì tilẹ sọ pé “”ki iṣe àfèkùnṣe, tàbí alaigbọdọ má ṣe””. Ọlọrun fẹ kí o fún ní nítorí ọkàn rẹ kún àkúnwọsílẹ fún ọpẹ. O fẹ ki o kí o ní ayọ àti inudidùn, ti o bá mú ọrẹ rẹ wá. O fẹràn oninu didun ọlọrẹ ! Ṣe àṣàrò lórí otitọ Ọlọrun loni. Ro nípa ohun tí o ti ṣe fún ọ. O gbà Ọ la, O ra ọ pada. Dúró lórí otitọ pe O npe se fún ọ. Bí o ti ṣe nṣe àṣaro lórí ìre Rẹ, ọkàn rẹ kun àkúnwọsílẹ fún ọpẹ, gẹgẹ bí àwọn amòye mẹta, fifunni ni lati jẹ ohun a i ronú ṣe.

Bibeli Kika: Matiu 2
ADURA:
Mo yàn láti ṣe àṣàrò lórí ìre Rẹ loni. Modupe fún ìfẹ igbala Rẹ fun mí. Mo dupẹ fún ìràpadà ayé mí kúrò nínú koto. Mo fún Ọ ní ohun gbogbo ti mo jẹ loni ni orúkọ Jésù Àmín.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *