Will There Be Eternal Punishment?

THE SEED
And I saw the dead, great and small, standing before the throne, and books were opened. Another book was opened, which is the book of life. Revelation 20:12

The thought of ungodly individuals receiving eternal torment is disliked by many people. Some believe that if God knew humans would sin, He shouldn’t have ever created the world. Can you, however, picture never having been born? Others believe that the ability to sin and commit evil should not have been given to man by the almighty Father. But if you had no freedom of choice or will, would you choose to be a robot? Our Father chose a different course of action and gave people free will when He created them. Man can choose to exalt the Creator after receiving affection from Him in this way. God gave us the freedom to choose between acts of obedience and disobedience, such as love or hate. He realised that making a decision meant that people might occasionally suffer, but they would also have the chance to develop as humans. God may then mould us as we develop in love and submission to Him; as a result, we shall take on His likeness. God realised that giving His creatures free will was the best course of action. How will you use yours? I hope you will recognise the price Jesus paid for you on the cross and decide to accept His love right now.

PRAYER
Help me oh Lord, I don’t want to be a partaker of the eternal punishment, but I want to be a partaker in the eternal life, so help me God, Amen.
BIBLE READINGSRevelation 20:11-15

NJE ÌJIYA AYERAYE YIO WA BI?

IRUGBIN NAA
Mo sì rí àwọn òkú, àgbà àti kékeré, wọ́n dúró níwájú ìtẹ́ náà, a sì í àwọn ìwé síle. A í ìwé mìíràn, èyí tí í e ìwé ìyè. Ifihan20:12.

Rironu nipa ijiya ti awon ènìyàn ti ko se ife Ólorun yio je, je oun ti opolopo ènìyàn ko nife si. Awon kan gbagbo pe ti Ólorun ba mo pe awon ènìyàn kan yio dese, iba ma da aye rara. Njẹ o kan ti ro bi iba se ri bi a kò ba bi o? Awọn miiran gbagbọ pe ko ye ki a Fi aye gba awon ènìyàn lati dese àti lati Wu iwà búburú lati odo Olorun. Ṣugbọn ti o ko ba ni ominira lati yan tabi se ohun to o Wu o, ṣe iwọ yoo yan lati jẹ ero atowoda bi? Bàbá wa yan ipa onà tó yàto, ó sì fún àwọn èèyàn lómìnira láti yan ohun tí wọ́n bá fẹ́ ṣe nígbà tó dá wọn. Eniyan le yan lati gbe Ẹlẹda ga lẹhin gbigba ifẹ lati ọdọ Rẹ ni ọna yii. Ọlọrun fun wa ni ominira lati yan laarin awọn iṣe ìgbọràn ati aigbọran, bii ifẹ tabi ikorira. Ó wá rí i pé ṣíṣe ìpinnu túmọ̀ sí pé àwọn èèyàn lè máa damu leekokan àmọ́ wọ́n tún láǹfààní láti dàgbà gẹ́gẹ́ bí èèyàn. Ọlọ́run lè mọ wá bí a ṣe ń dàgbà nínú ìfẹ́ àti ìtẹríba fún n; nítorí náà, àwa yóò gbé àwòrán Rẹ̀. Ọlọ́run wo pé fífún àwọn edá Re lómìnira láti ṣe ohun tó wù wọ́n je oun ti o Dara juli. Bawo ni iwọ yoo ṣe lo ominira tirẹ? Mo nireti pe iwọ yoo da idiyele ti Jesu san fun ọ lori agbelebu ki o pinnu lati gba ifẹ Rẹ ni bayi.

ADURA
Ran mi lowo Oluwa, nko fe je alabapin ninu ijiya ayeraye, sugbon mo fe je alabapin ninu iye ainipekun, nitorina ran mi lowo Olorun Amin.
BIBELI KIKA: Ìfihan 20:11-15

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *