You Cannot Sink When You Have Jesus Part 1

THE SEED
“Therefore will not we fear, though the earth be removed, and though the mountains be carried into the midst of the sea” Psalms 46: 2

When the supernatural combines with the natural, something far more superior results. For instance, when the limited ability of man is combined with the unlimited ability of God, the result can be very outstanding. When an axe head fell into the river in 2 Kings 6: 1-7, and the man of God took a piece of wood and threw it into the river, the wood sank like lead while the iron axe head began to float. This simply tells us that no loss is permanent. A loss remains a loss until the supernatural power of God comes into the situation. Anytime Jesus Christ- the Vine is introduced into a situation of loss, whatever was missing will be found. Also, just as the axe head swam to the fore, if you allow Jesus to be dipped into your life, all your hidden potentials and possibilities that the enemy probably thought they had securely caged would come to limelight.

BIBLE READING: 2 Kings 6: 1-7

PRAYER: In the name of Jesus Christ of Nazareth, every hidden or imprisoned talent, ability or potential in your life shall come to the surface from now on.

O KO LÈ TẸ RI NIGBATI O NI JÉSÙ (APÁ KINI)

IRUGBIN NAA
“Nítorí náà, a kì yóò bẹ̀rù, bí a tilẹ̀ ṣí ilẹ̀ ayé kúrò, àti bí a tilẹ̀ gbé àwọn òkè ńlá lọ sí àárín òkun.” Sáàmù 46:2

Nígbà tí ohun tí óju ẹ̀dá kò lè rí, bá darapọ̀ pẹ̀lú ohun tí a rí , ohun kan tí o dára jùlọ a máa ṣẹ yọ. Bí àpẹẹrẹ, nígbà tí agbára èèyàn tí a fí sí gbédeke bá dara pọ̀ mọ́ agbára Ọlọ́run tí kò ní ààlà, àbájáde rẹ̀ lè yọrí sí ohun pàtàkì tí kò ní àfiwé. 2 Ọba 6:1-7, – Nígbà tí orí àáké bọ́ sínú odò náà, ènìyàn Ọlọ́run náà sì mú igi kan, ó sì sọ ọ́ sínú odò náà, igi náà rì bí òjé, nígbà tí ààke ìgi ríi, àáké irin, sì bẹ̀rẹ̀ sí í léfo. Eleyi nìkan sọ fun wa wipe ko si pipadanu ti o wà títí. Ipadanu kan yio jẹ titi, a fi ti agbara airi ti Ọlọrun bá wa sinu ipo naa. Nigbakugba ti a bá ṣe àfihàn Jesu Kristi – Ti nṣe Ajara naa, sinu iru ipo ìpàdánù bẹ, ohunkohun ti o padanu yíó dì riri padà. Bákan náà, gẹ́gẹ́ bí orí àáké ti lúwẹ̀ sí etí okun. Ti o bá jẹ́ kí Jésù wọ inú ìgbésí ayé rẹ lọ, gbogbo ohun a mu ṣògo ti o lè fara pa mọ́, àti awọn ohun tí àwọn ọ̀tá rò pé wọ́n ti há sínú ipamọ yóò wá sí imọlẹ.

BIBELI KIKA: 2 Ọba 6:1-7

ADURA: Ni orúkọ Jesu Kristi ti Nasarẹti, gbogbo talenti, ti o farasin tabi ti o wa nínú ẹwọn ayé yoo wa si oke lati igba yii lọ.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *