Have You Forgotten So Soon?

THE SEED
“Nevertheless, I have somewhat against thee because thou hast left thy first love.” Revelation 2:4-5[KJV]

Many a times the already redeemed soul feel dissatisfied amid believers and the presence of God. The sermon is not meaningful again, prayers seem like noise, even quiet moments with God is being disturbed by distractions. Memory of intimacy with Christ make the soul shiver, like the time God called on Adam in the garden of Eden where he was hiding because he ate from the tree of knowledge of good and evil, disobeying God’s instruction. The first love became cold. Be awakened! Remember therefore where you have fallen. Repent, and start doing the work you were doing at first. The door is not locked, you can have a good relationship with God in Christ again. He has given you more breadth that you might use to seek, cry, and wait on Him. Even the disciples of Jesus after His death, went back to fishing. They would have remained purposeless if not for the love He had for them to call them back to Himself. Even Simon Peter, of all people, has to jump into the sea
when he realized that Jesus has resurrected, and He came looking for them. He felt ashamed of himself.

PRAYER
Help us o Lord, hold us tightly so as not to stray away from Thy presence when we are weak in Jesus Name. Amen.
BIBLE READINGS: Revelations 2:1-7

NJE O TI GBAGBE NI KIAKIA?

IRUGBIN NAA
“Sugbon eyi ni mo ri wi si o pe iwo ti fi ife re isaaju sile” Ifihan 2:4-5

Ni opo igba, awon onigbagbo ti a ti rapada ma nse aini inu didun si awon isele ti n sele laarin awon onigbagbo ati ni iwaju Olorun. Iwaasu ko ni itumo mo, adura dabi ariwo, asiko idakeje pelu Olorun ma nri idiwo. Ajosepo pelu Kristi ma nje ki okan gbon, bii igba ti olorun pe Adam ninu ogba Edeni nibi ti o ti nsa pamo nitori wipe o je eso ti oluwa ni ki o ma je. Ife akoko re wa tutu, e taji, e ranti ibi ti e ti subu. E ronupiwada ki e pada si idi ise ti e nse lati eyin wa. Ilekun wa ni sisi, e tun le ni ajosepo pelu Olorun ninu Kristi leekan si. O ti fun o ni eemi ti waa fi wa oju re. Lehin iku Jesu, awon omo eyin re pada si ise apeja. Aye won i ba ma ni itumo ti iba se wipe O pe won pada si odo re. Simoni Peteru, tile be sinu omi nigba ti o ri wipe Jesu ti jinde, tio si nwa won. Oju ara re tii.

ADURA
Oluwa e ran wa lowo, e di wa mu sinsin ki a ma baa sako lo kuro niwaju yin nigba ti a se aare, ni oruko Jesu, Amin.
BIBELI KIKA: Ifihan 2:1-7

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *