THE SEED
“The earth is the Lord’s, and the fulness thereof; the world, and they that dwell therein.” – Psalm 24:1 (KJV)
God owns everything, and His plans for His children are always good. Yet, when situations grow tough, His promises can begin to feel distant, and we’re tempted to settle for less. But God’s Word is sure. He can move circumstances, people, and resources to bring His perfect plan to pass.
The question is not whether God can provide—it’s whether we will trust and wait for His best. Don’t let weariness or delay make you accept a lesser alternative. His promises are sure, and His timing is perfect.
BIBLE READINGS: Isaiah 55:8–13 (KJV)
PRAYER: Father, help me not to settle for less than Your perfect will. In seasons of delay, strengthen my heart to hold on to Your Word. Amen.
DIDI ORO OLORUN MU
IRUGBIN NAA
TI Oluwa ni ilẹ, ati ẹkún rẹ̀; aiye, ati awọn ti o tẹdo sinu rẹ̀. Orin Dafidi 24:1
Olorun lo ni ohun gbogbo, ero Re fun awon omo Re ni igba gbogbo, rere ni. Sibe, nigbati isoro ba le, ileri Re le dabi eni pe o jina, a si le fe se amulo ohun ti a ri lakoko naa sugbon Oro Olorun daju. O le yi aye wa pada, o le lo eniyan ati ohun elo, lati mu ero pipe RE se. Boya Olorun le pese ko ni ibeere, bikose boya a o le gbekele, ki a si duro fun eyi ti o dara julo. Mase je ki irewesi tabi idaduro ki o mu o gba ohun ti ko dara to. Awon ileri Re daju, asiko Re lo si dara ju.
BIBELI KIKA: Isaiah 55: 8-13
ADURA: Baba, ran mi lowo lati mase gba ohun ti o kere si eto Re ti o pe. Ni akoko idaduro, mu okan mi le lati di oro Re mu. Amin