BEWARE OF THE TRAP OF POSITION
THE SEED
“Be not deceived; God is not mocked: for whatsoever a man soweth, that shall he also reap.” — Galatians 6:7 (KJV)
Every position in life whether in church, work, or society is both a privilege and a responsibility. How we treat others today shapes how we will be treated tomorrow. Arrogance, pride, or neglect can turn our blessings into traps. Ruth’s kindness to Naomi opened a door to destiny. Likewise, how we steward our roles impacts our future. Positions are temporary, but character is lasting. The higher we rise, the more humility we must embrace. Do not let spiritual gifts or earthly success make you proud. Keep your eyes on Jesus, the author and finisher of your faith.
Reflection: Your position is a platform to serve, not a pedestal to fall from.
BIBLE READING: Galatians 6:4–10
PRAYER: Father, keep me humble in every position You place me. Let my actions today build a legacy that honours You. Amen.
SORA FUN PANPE IPO
IRUGBIN NAA:
Ki a máṣe tàn nyin jẹ; a kò le gàn Ọlọrun: nitori ohunkohun ti enia ba funrugbin, on ni yio si ká. Galatia 6:7
Gbogbo ipo laye, yala ninu ile ijosin, nibi ise tabi lawujo, o je oreofe ati ojuse. Ohun ti a ba se fun elomiran loni ni yio juwe ohun ti won yoo se si wa lojo ola. Iwa agidi, igberaga tabi ainani le yi ibukun wa pada si panpe. Iwa rere ti Rutu wu si Naomi ni o si ilekun ayanmo won. Bakannaa, bi a ti se ise iriju wa ni ipa lori ojo iwaju wa. Fun igba die ni ipo, sugbon titi aye ni iwa. Bi a ba se nga ni ipo si, beeni a gbodo ni iwa irele to. Mase je ki ebun emi tabi aseyori ninu aye yii mu o gberaga. Gbe oju re le Jesu, olupilese ati alasepe igbagbo re.
ERO: Ipo re fun o ni anfani lati sise, kiise lati gbe o subu.
BIBELI KIKA: Galatia 6:4-10
ADURA: Baba, fun mi ni emi irele ni ipokipo ti o fimisi. Je ki iwa mi fi ola fun o.