LIVING THE NEW LIFE IN CHRIST

LIVING THE NEW LIFE IN CHRIST

THE SEED

“Therefore, if anyone is in Christ, he is a new creation; old things have passed away; behold, all things have become new.” — 2 Corinthians 5:17 (NKJV)

Being in Christ is more than a confession; it is a transformation. The new life replaces old patterns of sin with the fruit of the Spirit—love, joy, peace, patience, kindness, goodness, faithfulness, gentleness, and self-control.

Many Christians still struggle with living between the old and new because they haven’t fully surrendered to the Spirit’s transforming work. Wilful sins can slowly erode spiritual growth if left unchecked. That is why David prayed in Psalm 19:13, “Keep me from wilful sins, may they not rule over me.” Let your new identity in Christ reflect in your character, your choices, and your daily walk. Live like one who has been made new.

Reflection: The proof of new life in Christ is daily transformation.

 

BIBLE READING: 2 Corinthians 5:16–21

PRAYER: Lord, thank You for making me a new creation. Help me to live fully in my new identity in Christ. Amen.

 

GBIGBE AYE TITUN NINU KRISTI

IRUGBIN NAA:

“Nítorí náà bí ẹnìkan bá wà nínú Kristi, ó di ẹ̀dá tuntun: ohun àtijọ́ ti kọjá lọ; kíyèsi i, ohun tuntun ti dé.” II Korinti 5:17

Wiwa ninu Kristi kọjá ijewo nikan; o je iyipada. Aye titun yoo ropo igbe aye atijo pelu eso ti Emi- eyi ti n se ife, ayo, alaafia, suuru, isoore, isotito, iwa-pele ati iko ara eni ni ijanu. Opolopo Kristeni ni o ṣi n ja ijakadi larin igbe aye atijo ati igbe aye titun nitori won ko tii jowo ara won patapata fun ise Emi Mimo eyi tin so eni di otun. Awon ese ti a moomo da le ba idagbasoke Emi je die die ti a ko ba dekun won. Eyi lo je ki Dafidi gbadura ni Orin Dafidi 19:13 “Wẹ ìránṣẹ́ rẹ mọ́ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ àmọ̀ọ́n-mọ̀-dá; má ṣe jẹ kí wọn kí ó jẹ ọba lórí mi.…” Je ki eda titun re ninu Kriti farahan ninu ise, ipinu, ati irin ojoojumo re. Máa gbé gege bi eni ti a ti so di otun.

Asaro: Eri aye titun ninu Kristi ni iyipada ojoojumo.

 

BIBELI KIKA: II Korinti 5:16-21

ADURA: Oluwa, E se wipe O da mi ni eda titun, ran mi lowo lati maa gbe gege bi eda titun ninu Kristi ni kikun. Amin.

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *