ACTS OF THE FINGER OF GOD
THE SEED
“Then the magicians said to Pharaoh, ‘This is the finger of God” Exodus 8:19a KJV
In the Scripture above, the Egyptian magicians employed by Pharaoh tried and were able to produce counterfeit miracles through their enchantments twice. But on this particular occasion, they tried hard but failed woefully. And they confessed to the superiority of God’s power. Likewise in any battle that confronts the children of God, the enemy has an expiry date. The devil and his agents may manipulate situations and may appear to have the upper hand, but no matter how long and turbulent the battle may be, God is always a victor. Some of the wonders the ‘finger of God’ will do is to confuse, disgrace and defeat the enemy, but disobedience, sin, ignorance, rebellion on the part of the children of God can hinder the move of the finger of God.
To activate the Finger of God, it is imperative that you must be born again and pray fervently.
PRAYER
My Father, let the Finger of God defeat every adversary of my soul in Jesus name. Amen BIBLE READINGS: Exodus 8:16-19a
ÌṢE TI ÌKA OLORUN
IRÚGBÌN NÁÀ
” Nigbana ni awon alalupayida wi fun Farao pe, Ika Olorun li eyi “Eksodu 8:19a. Ninu eko kika wa, awon alalupayida Egipiti ti o je alabasisepo Farao gbiyanju lati se ayederu ise iyanu nipa idan won, nigba meji. Sugbon ni akoko kan won gbiyanju, won si ni ijakule jojo. Won si jeri titobi Olorun. Bakan naa ninu ogun ti o dojuko awon omo Olorun, igba ati akoko awon ota maa ndopin. Esu ati awon omo ogun re maa nlo ayidayida lori awon idojuko; eyi ti yio jo wipe won fe jagun bori. Sugbon bi o ti wu ki ogun naa pe to, ti iji naa si le, Olorun ni olusegun.
Die ninu ise iyanu ti ika Olorun maa nse ni lati ran iporuru, itiju ati aseti si awon ota. Sugbon aigboran, ese, aini imo, isote, ni ona awon omo Olorun, le se idena fun bi ika Olorun se lee rin laarin awon omo Olorun. Lati le mu ika Olorun wa si ojuse o pon dandan lati di atunbi, ki o si maa gbadura nigbagbogbo.
ADURA
Baba mi, jeki ika Olorun fun awon ogun ti o fun okan mi, ni ijalule. Amin
BIBELI KIKA: Eksodu 8:16-19a