PRAYER MANNERS
THE SEED
“Our Father which art in heaven, Hallowed be thy name.” Matthew 6:9
Jesus Christ did not want His first disciples and those of today to pray amiss, so He gave a format for prayer. First of all, you need to acknowledge God as your Father; meaning you need to have a personal relationship with Him. Secondly, worship and praise Him, and welcome His presence. Thirdly, ask for His will to be done in your life as it is in heaven. Fourthly, ask for your pressing needs, especially your daily provision. Fifthly, forgive all who have wronged you and ask God to also forgive you for your sins. Lastly, pray for His power of deliverance from evil and temptation.
Dearly beloved, as believers, we should always ascribe praise unto Him. When we are about to pray, we should have these layouts on our mind, especially worship/praise, and thanksgiving before our request; as we do these in faith and receive in faith, every prayer we make will be made according to the Lord’s leading. Thus, it is necessary to have that continual relationship with the Father through prayer, not just when tragedy strikes. You will therefore radiate with the glory of God.
PRAYER
Father, thank you for teaching me how to pray. Amen.
BIBLE READINGS: Matthew 6:5-13
BI A TI N GBA ADURA
IRUGBIN NAA
“Nitorinaa, bayi ni ki eyin maa gbadura, Baba wa ti mbe li Orun, ki a bowo fun oruko re.” Matteu 6:9.
Jesu Kristi ko fe ki awon omo eyin re nigba ni ati awon ti isisiyi ko si beere, tori naa o fi alakale adura gbigba lele. Lakoko, o gbodo gba wipe baba re ni Olorun n se, eyi ti o tumo si pe o gbodo ni ibasepo ti o dara pelu re. Ekeji, fi iyin ati ola fun, ki o si pee sokale. Eketa, bere pe ki ife tire o se ninu aye re bi won ti n se ni orun. Ekarin, beere ohun ti o se alaini, pataki julo ounje oojo re. Ekarun, dari ese ji gbogbo awon ti o se o, ki o si beere pe ki Oluwa ki o dari ese tire ji o bakan naa. Ipari, gbadura fun agbara itusile lowo bilisi ati idanwo.
Olufe owon, gege bi onigbagbo, a gbodo maa da gbogbo ogo pada sodo Olorun. Nigbakigba ti a ba fe gba adura, a gbodo ni awon alakale adura wonyi lokan pataki julo ope/iyin saaju ibeere, bi a ti n se eleyi pelu igbagbo ti a si n ri gba pelu igbagbo, gbogbo adura ti a ba gba
yio je pelu idari Olorun. Nitorinaa, o se pataki ki a ni ajosepo ti o dara pelu Baba nipase adura, kii se nigbati isoro ba de nikan sugbon ki a maa baa soro nigba de igba. Ogo Oluwa yio si buyo lara re.
ADURA
Baba, mo dupe wipe o ko mi bi a ti n gba adura. Amin.
BIBELI KIKA: Matiu 6: 5-13