Power Of Reconciliation To All Christians

THE SEED
“Now all things are of God, who has reconciled us to Himself through Jesus Christ, and has given us the ministry of reconciliation…” 2 Corinthians 5:18

A significant number of us have been deserted, sold out or mishandled. Moves made against us left scars on our spirits, persistent resentment, or deep harshness. Those offenses killed our genuine peace of mind. We have a Saviour that we deserted. We abandoned our faith to pursue lesser things. We injured Him and stored up injustice against Him. Despite this, He exhausted Himself of all heavenly royalty and lowered Himself to the mark of death on the cross… even while we were still sinners. Whenever we go to him for forgiveness, He opened His arms and give us access to His grace. He accommodated us to God. He picked forgiveness, washed away the transgressions of the past, and wouldn’t recall them any longer. He gave us the ministry of reconciliation. He mended our wrong relationship with the Father, so we can show others the way back to Him. Through Christ, our wrong associations with others can be healed as well. He enables us to pardon, giving us the ability to rise and live freely. He breaks the extremely tight grips of outrage and harshness. He alone brings the hope and healing, the reconciliation and restoration, the opportunity, and a future. He ministered reconciliation and charges us to do likewise.

PRAYER
Father Lord give me the ministry of reconciliation that I may live in peace with all men as Christ did. Amen.

BIBLE READINGS: 2 Corinthians 5: 11-21
AGBARA ILAJA FÚN GBOGBO KRISTẸNI
IRÚGBÌN NÁÀ
“Ohun gbogbo sí tí ọdọ Ọlọrun wá, eniti o sì tí ipàsẹ Jesu Kristi bá wá lájá sọdọ ará Rẹ, tí o sì tí fí iṣẹ-iranṣẹ ilaja fún wa.” 2 Kọrinti 5:18.

Púpọ ninu wá, ní a ti kọ sílẹ, tí a sì à tà wa danu, a sì fí ọwọ ai laanu mú wa. Igbesẹ tí a ṣe lodi sí wá ti fí ãpá sí ara ẹmi wa, ikọsilẹ ìgbàgbogbo, tàbí ìlò ipá tí o jinlẹ̀. Awọn ẹṣẹ wọ̀ nyí tí pá alaafia to péye rún ninu ọkan wa. A ní Olugbala ti a kọ sílẹ. A kọ ìgbàgbọ wa silẹ láti rà ohun ti kò ní yé lori. A pá a lára, a sì kó àwọn aisododo jọ lòdì sí. La i ká èyí kún, O ru ara rẹ soke, pẹlu ọla atoke wa. O sì tún rẹ Ará rẹ silẹ fún àmì iku lori igi agbelebu…. nígbàtí a jẹ ẹlẹṣẹ. Nígbàkúùgbà ti a ba tọ́ ọ lọ fún Idariji ẹṣẹ, yíó là ọwọ Rẹ lati fún wa laaye sí oore ọfẹ Rẹ. O faye gba wa sọdọ Ọlọrun. O mú Idariji, O sì fi wẹ aiṣedede wá atẹhinwa nu, kò sí ní rántí wọn mọ. O fí iṣẹ iransẹ ilaja fún wa. O tún ibaṣepọ wá tí ko dúró dede pẹlu Ọlọrun ṣe; ki a ba le fí ọna ipadà sí ọdọ Ọlọrun hàn fún àwọn ẹlòmíràn. Nipasẹ Kristi, ikẹgbẹ pọ pẹlú àwọn mìíràn tí kò tọna lèé gba ìwòsàn. O ran wa lọwọ láti d’áríjì O fún wa ni òkun láti dìde àti láti gbé ìgbé ayé ominira. O fọ inilara ati ọwọ líle. Òun nìkan Ni o fún wa ni ìrètí, ìwòsàn, ilaja, àti imubọsipo, anfaani ati ọjọ iwájú. O fí iṣẹ ilaja fún wá o sì rọ wà láti ṣe bẹẹ gẹ́gẹ́.

ADURA
Bàbá wa, Olúwa fún mí ni iṣẹ iransẹ ilaja lati wà li alafia pẹlu eniyan gbogbo. Àmìn

BIBELI KIKA: 2 Korinti 5: 11-21

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *