Loved By Christ

THE SEED
“As the Father hath loved me, so have I loved you: continue ye in my love.” John 15:9

It’s obviously true that the Son of God loves us. That is worth considering. He who loves you is God Himself, who is heavenly, who is in the right hand of God, and has all power in heaven and on the earth. Consider too what His affection for you set him back. It cost Him His own life. It cost Him a death on the cross. Consider what you have because of the affection of the Son of God. In view of His affection, you have liberation. You are not generally bound to get what you merit for wrongdoing, specifically, eternal damnation in Hell. You no longer have to face the fury and wrath of almighty God. All things considered, in light of His adoration for you, you will get and appreciate everlasting life in heavenly glory. His love is very, very valuable to every child of God. Sincerely adored, so extraordinary is His love, that His adoration works in us the certainty to accept that He, the all-powerful Son of God, who is sovereign in everything, will make sure that nothing removes us from Him. That makes us sure of the reality of His Salvation.

PRAYER
Let your love for me O God, not be stained by the affection of this world in Jesus name Amen.

BIBLE READINGS: John 15: 9-17

KRISTI FẸ WÁ
IRÚGBÌN NÁÀ
“Gẹgẹ bí Bàbá ti fẹ mi, bẹli èmi sì fẹ yín: ẹ dúró nínú ìfẹ mi.” Johannu 15: 9

O hàn gbangba lotitọ pé Ọmọ Ọlọrun fẹ wá. Èyí yẹ fún àgbéyẹ̀wò. Ẹnití o fẹ ọ gán ní Ọlọrun fúnra rẹ tí o wà lọrùn, ti o wà ní ọwọ ọtún Ọlọrun, tí o sì ni agbára lọrùn àti ní ayé. Ronú nípa ìfẹ Rẹ sí ọ, O naa ni ayé Rẹ̀ fún rà rẹ , O naa ní ikú Rẹ lóri ìgi agbelebu . Ronú nípa ohun tí o ni lati ipasẹ ìfẹ Ọmọ Ọlọrun sí ọ. Tí a bá wo ifẹ Rẹ sí ọ, iwọ ti ní itusilẹ, kúrò lọwọ ìjìyà fún àwọn aṣiṣe rẹ, ti o le mu ọ jẹ ẹni egbe ní ọ̀run apaadi. O kò nilo lati d’ojukọ ìbínú àti ìrúnú Ọlọrun Olódùmarè. Ní ìdí èyí pẹlú ìfẹ tí o ní sí ọ, iwọ yíó gbà ìyè àìnípẹkun nínú ògo ọ̀run. Ìfẹ Rẹ jẹ iyebiye fún ọmọ Ọlọrun k’ọkan. Ailakawe ìfẹ Rẹ sí wá fí titobi agbara rẹ hàn lori ohungbogbo, ti yíó fí dáwà lójú pé kò sí ohun tí o lè mú wa kúrò lọdọ Rẹ. Èyí ni idaniloju igbala Rẹ.

ADURA
Jẹ́kí ìfẹ Rẹ fun mí Ọlọrun, máṣe ní abawọn nípa ìfẹ fún ohun ayé yi. Amin.

BIBELI KIKA: Johannu 15: 9-17

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *