THE SEED
“Stand fast therefore in the liberty wherewith Christ hath made us free, and be not entangled again with the yoke of bondage.” Galatians 5:1
With our spiritual opportunity comes a few spiritual obligations that we should establish in our lives! The opportunity discussed here is more than political opportunity. It is an opportunity which no one but God can give and it shows up when the Spirit of the Lord shows up. It is spiritual freedom – it is independence from the chains of sins. It is actually the case that all individuals deserve a privilege of opportunity – yet it is additionally a fact that you won’t encounter genuine opportunity until you experience “the Spirit of the Lord”. For – “Where the Spirit of the Lord is, there is freedom” (2 Corinthians 3:17). Spiritual opportunity is the most impressive opportunity there is – it is the freedom of being free from sin. God can liberate you. He can liberate you from the bondage of sin. He can liberate you from the punishment of sin. He can liberate you from the guilt of sin. He can liberate you from the penalty of sin. God has expanded a pardon – a pardon to the highest level. The opportunity we experience through Christ brings deliverance to our lives. Freedom from the guilt and power of sin, and deliverance from craft of the flesh
PRAYER
Father Lord I thank you for the opportunity to attain spiritual freedom from the guilt and power of sin.
BIBLE READINGS: John 8: 21-30; Galatians 5:1-12
ITUSILẸ NÍNÚ Ẹ̀MI
IRÚGBÌN NÁÀ
“Nitorina ẹ́ duro ṣinṣin ninu ominira na èyítí Kristi fí sọ wá di òmìnira, kí a má sì ṣe tún fí ọ́run bọ àjàgà ẹrú mọ” Galatia 5:1
Anfani ti o wà nipa ti ẹ̀mí wá pẹlu dandan tí ẹ̀mí, tí a nilati fí ẹsẹ rẹ múlẹ nínú ayé wa. Anfani ti a ngbe yẹwo yi jù anfani tí o wà nínú oṣelu lọ. Anfani ẹ̀yi ti ẹnikẹni kò lè fún ní, àfi
Ọlọrun nikan ni o le fún ní; eyi sí máa njẹ́yọ́ nigbati ẹ̀mi Oluwa ba farahan. Èyí jẹ́ itusilẹ nipa tí ẹ̀mí – èyí ni òmìnira kúrò ninú ide ẹ̀ṣẹ̀. O jẹ ohun ti o yẹ lati ní irú anfani yi, ṣugbọn otitọ ibẹ ni pe a kò lè ní ojúlówó anfani yi, a fi ki a ní ìrírí nípa ẹ̀mi Oluwa. Nitoripe ní ibi tí ẹ̀mí Oluwa ba wa “Itusilẹ́ yíó wà níbẹ” (2 Kọrinti 3:17). Anfani ti ẹ̀mí ni, anfani ti o dára jù -O jẹ anfani lati ni ominira kuro ninu ẹsẹ. Ọlọrun lè tú ọ silẹ. O lè tú ọ silẹ kúrò nínú ìdè ẹṣẹ. O lè tú ọ silẹ kúrò nínú ijiya ẹṣẹ. O lè tú ọ silẹ kúrò nínú ẹ́bi ẹ̀ṣẹ. O lè tú ọ silẹ kúrò lọwọ ìdálẹbi ẹṣẹ. Oluwa tí mú Idariji gbooro, Idariji tí o ga jù. Anfani ti a ní láti ọdọ Kristi mu idande wá fún ayé wà. Ominira kuro ninu ẹbi ati agbara ẹṣẹ àti Itusilẹ́ kúrò lọwọ arekereke ẹran ara.
ADURA
Bàbá wa ati Oluwa wa mo dúpẹ́ fún anfani ominira ti ẹ̀mí kúrò lọwọ ẹ̀bi ati agbara ẹṣẹ Àmìn.
BIBELI KIKA: Johannu 8: 21-30; Galatia 5:1-12