Girded With Truth And The Breastplate Of Righteousness

THE SEED
Stand therefore, having girded your waist with truth, having put on the breastplate of righteousness. Ephesians 6:14

It is crucial to always be prepared, ready to fight, because our spiritual warfare has no breaks. Knowing the truth of God’s Word is the most important part of our armor. Only the “belt of truth” allows us to move freely and holds our offense and defense weapons in place, just as the belt of the Roman soldier kept all his armor pieces in place. The belt also held the sheath in which they carried their sword. If we only hear the truth, without “knowing” it, it is not enough to be free, as Jesus said in John 8:32. The truth of the Bible revealed by the Holy Spirit, becomes “living and working” (Hebrews 4:12) in our hearts where it convinces, teaches, transforms us and it becomes a fearsome weapon in spiritual warfare, when we proclaim it. The “breastplate of righteousness” is the piece of armor that protects the vital organs, especially the heart. In the Bible, the “heart” is not the physical organ that maintains physical life, but it refers to the “inner man,” that is the spirit of the person who is “born-again” by the Holy Spirit when they sincerely repent of their sins and believe upon Jesus. We can be righteous, (which means without sin) only through the sacrifice of Jesus. If we truly ask God to forgive us when we sin and regret what we have done, the Lord is faithful and just enough to forgive us. When the enemy comes to condemn us for the sins we have already repented of, we need to realize that we are forgiven, have on the “breastplate of righteousness” and we can resist the enemy’s accusations in the Name of Jesus. The enemy’s attack will fail if we realize that when we repented with all our hearts the Lord forgave us, “casting all our sins into the depths of the sea” (Micah 7:19b), meaning that our sins are gone forever.

BIBLE READING: JOHN 8, MICAH 7

PRAYER: Praise You Lord for the truth of Your Word. Thank You so much for making it available for me so that I can study and learn it to be able to recognize the lies of the enemy and stand firm against them, by proclaiming Your Word. Thank You with all my heart dear Jesus for forgiving my sins and for Your righteousness that covers me. Lord please help me remember that once I sincerely repent and asked for forgiveness of my sin, I am forgiven so that whenever the enemy comes with thoughts that condemn me of what I did in the past, I will know it is not You and I will resist him in the Name of Jesus, amen.

TI A FI AMURE ÒTÍTỌ ATI IGBAYA ODODO DI.

IRUGBIN NAA
Ẹ dúró nitorina lẹhin ti ẹ fi amure otitọ di ẹgbẹ yin, ti ẹ sí ti di igbaya òdodo ni amure. Efesu 6:14.

Ó ṣe pàtàkì pé kí a wa ni imúra sílẹ̀ nígbà gbogbo, kí a ṣetan láti jagun, nítorí pé ogun ẹ̀mí jija wa n tẹ siwaju. Mí mọ òtítọ́ ọrọ̀ Ọlọ́run ṣe pàtàkì jù lọ nínú ìhámọ́ra wa. Kìkì “igbànú òtítọ́” nìkan ló ń jẹ́ ká lè máa rìn bí a tí fẹ, ká sì di ohun ìjà ìkọsẹ̀ àti ohun ìjà ìgbènijà wa, sí àyè tí tọ. Gẹ́gẹ́ bí ìgbànú ọmọ ogun ilẹ Róòmù ṣe npa gbogbo ìhámọ́ra rẹ̀ mọ́. Àmùrè náà tún di àkọ̀ tí wọ́n gbé idà wọn sí nínú. Ti a ba gbọ otitọ nikan, ti a kò sí “mọọ” , ko to lati ni ominira, gẹgẹ bi Jesu ti sọ ninu Johannu 8:32. Òtítọ́ inú Bíbélì bi Ẹ̀mí Mímọ́ ti ṣí i payá, di “alààyè tí ó sì ń ṣiṣẹ” (Hébérù 4:12) nínú ọkàn wa, níbi tí ó ti ńda wa lójú, tí o ti ń kọ́ni, ti ó nyí wa padà: tí ó sì di ohun ìjà tí o bá ni lẹ́rù nínú ogun jija ti ẹ̀mí, nígbà tí a bá ń kéde rẹ̀.“Àwo ìgbàyà òdodo” jẹ́ apá kan ìhámọ́ra tí ń dáàbò bo àwọn ẹ̀yà ara pàtàkì, ní ibi pàtàkì ọkàn. Nínú Bíbélì, “ookàn-àyà” kì í ṣe ẹ̀yà ara tó ń pa ìwàláàyè mọ́, ṣugbọn ó ń tọ́ka sí “ènìyàn ti inú,” eyi jẹ ẹmi ẹnití “a tún bí” nipasẹ ẹmi mímọ nígbà tí wọ́n bá ronú pìwà dà tọkàntọkàn fún ẹ̀ṣẹ wọn ki o si gbagbọ nipasẹ Jesu. A le jẹ olododo, (eyi ti o túmọ sí lai l’ẹṣẹ) nikan nipa ẹbọ Jesu. Tí a bá bẹ Ọlọ́run lóòótọ́ pé kó dárí jì wá nígbà tá a bá ṣẹ̀ tí a sì kábàámọ̀ ohun tá a ṣe, Jèhófà jẹ́ olóòótọ́, ó sì tó láti dárí jì wá. Nígbà tí ọ̀tá bá dé láti dá wa lẹ́bi fún àwọn ẹ̀ṣẹ̀ tí a ti ronú pìwà dà rẹ tẹ́lẹ̀, a ní láti mọ̀ pé a ti dárí jì wá, ki a sì ní “ ìgbàyà òdodo” àti pé a lè kọjú ìjà sí àwọn ẹ̀ṣù ti nṣe ọ̀tá ní orúkọ Jésù. Ìkọlù àwọn ọ̀tá yóò kùnà bí a bá mọ̀ pé nígbà tí a bá ronú pìwà dà pẹ̀lú gbogbo ọkàn wa, Olúwa ti dárí jì wá, “ó ń sọ gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wa sínú ọ̀gbun òkun” (Míkà 7:19b), tó túmọ̀ sí pé àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa ti lọ títí láé.

BIBELI KIKA: Johanu 8, Mika 7:19b

ADURA: Yin Oluwa fun otitọ ọrọ Rẹ. Ẹ ṣeun pupọ ti ẹ jẹki o wa larọwọ to fun mi ki n le ṣe iwadi ati kọ ẹkọ. Lati le mọ awọn irọ́ ọta, lati le duro ṣinṣin lòdì si wọn, nipa sisọ ọ̀rọ Rẹ. Mo dupẹ pẹlu gbogbo ọkan mi, Jesu olufẹ, fun idariji ẹṣẹ mi ati fun ododo Rẹ ti o bo mi. Oluwa jọwọ ranmi lọwọ lati ranti wipe, ni kete ti mo ba ronupiwada tọkàntọkàn ti mo si tọrọ idariji ẹṣẹ mi, a dariji mi; pe nigbakugba ti ọta ba wa pẹlú erongba lati da mi lẹbi ohun ti mo ṣe tẹlẹ, emi yio mọ pe kii ṣe Iwọ ati pe emi o dojukọ lórúkọ Jesu, amin.

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *