A Touch From God

THE SEED
“Then Jesus answered and said unto her, O woman, great is thy faith: be it unto thee even as thou wilt. And her daughter was made whole from that very hour.” Matthew 15:28

You can touch God with your prayers. In our Bible reading for today. Bartimaeus cried until Jesus stood still. Jesus was touched by Bartimaeus’ persistent calls. There are gentlemanly prayers – which people pray softly, sophisticatedly, with big grammar and careful diction. There are also prayers that can touch God – usually persistent in nature. In Luke 18:1-8, Jesus gave an example of a prayer that would definitely touch God. In fact, He said the prayer would touch even a wicked fellow, not to mention God. Some people pray for a while and stop when they haven’t gotten a miracle. Why are you stopping? Do you have another option apart from God? I have had the privilege of going to see some Presidents and when you get there you cannot be in a hurry. You get there before the time of appointment that was given to you, yet you may have to wait for some time before you get to see the President. On some occasions, it is the President who wanted to see me, yet l had to wait. How can you then go before the President of Presidents and say because He hasn’t attended to your request that you want to leave? If you leave, who will be affected? God remains God whether you pray or not, but you are nothing without Him. When you tarry in the place of prayer, He is touched and then gives you whatever you want. Even the woman with her daughter in Matthew 15:22-28, didn’t stop until Jesus answered her, It will show in how long you pray. Many people are still struggling with their problems because they stopped praying too early. Let that not be your story.

BIBLE READING: Mark 10:46-52

PRAYER: Oh Lord God, give me the power for breakthrough prayers. Help me to pray persistently.

IFOWOKAN LATI ODO ỌLORUN

IRUGBIN NAA
“Nigbana ni Jesu dahùn o si wi fun u pe, Iwọ obinrin, igbagbo rẹ tobi: ki o ri fun ọ gẹgẹ bi iwọ ti nfẹ. A sì mú ọmọbìnrin re lára dá láti wákàtí yẹn gan-an.” (Mátíù 15:28)

O le fi ọwọ kan Ọlọrun pẹlu adura rẹ. Ninu kika Bibeli wa loni, Bartimeu sọkún títí Jesu fi dúró je e. Aidake Batimeu kan Jesu Lara. Awon adura irele kan wa, eyi ti awon ènìyàn maa n gba ni pele kutu pelú oyibo nlanla ati asalo ede. Awon adura kan si wa ti o ma n kan Ọlorun Lara. Papa julo eyiti a n tenumo no gbogbo igba. Ninu IWE Luku 18:1-8 , Jesu se apẹẹrẹ adura eyi ti kole sai kan Ọlọrun Lara. Notooto o so pe iru adura be a maa kan eni buburu Lara, ki a ma tun so wipe Ọlorun. Awọn eniyan kan wa ti won a gbadura fun igba diẹ,wọn a si Dani duro nigbati wọn ko ti ri iṣẹ iyanu kan. Kini idi ti o fi duro? Ṣe o ni aṣayan miiran yatọ si Ọlọrun? Mo ti ni anfani lati lọ ri awọn Aare kan ati pe nigbati o ba de ibẹ o ko le ma a kanju. Iwo yio to debe saaju àkoko ti a fun O si be. Iwo yio duro pe die ki o to dipe O ri Aare naa. Lawon igba Miran, Aare ni yio Fe ri mi, síbe mo ni Lati duro. Bawo ni o ṣe le lọ siwaju Oba awon Oba ki o wa kuro níbe nitori ti ko Tete da o lohun? Ti Iwo ba binu lo, Tani yio pa Lara? Ọlọrun n je Ọlọrun sibe yala o gbadura tabi o ko gbadura ṣugbọn iwọ kii ṣe nkankan laisi Rẹ. Nigbati o ba durope ni ibi adura, Ọlorun yi o mo o Lara, yi o si fun o ni ohun ti o ba n fe. Obinrin ti o wa pẹlu ọmọbirin rẹ ni Matteu 15: 22-28, ko duro titi Jesu fi da a lohùn pe, Yoo fihan ninu bi o ti peto ti o ti n gba adura. Opo èèyàn ló ṣì ń bá ìṣòro wọn fínra nitori ti won tete Dake adura. Mase je ki eleyi o je iriri re

BIBELI KIKA: Máàkù 10:46-52 (KJV).

ADURA: Oluwa Ọlọrun, fun mi ni agbara fun awọn adura itusilẹ. Ran mi lọwọ lati gbadura nigbagbogbo.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *