Caveat Emptor

THE SEED
Beware lest any man spoil you through philosophy and vain deceit, after the tradition of men, after the rudiments of the world, and not after Christ. Colossians 2:8

The apostle Paul warned the Colossian church of the enemy’s plan to get them back into his web. The devil intended to accomplish this through philosophy and hollow deception with regard to custom and basic worldly values. The enemy’s and his dark allies’ strategy is still in effect today. He has added topics and courses to the curriculum that aim to insult our beliefs.
The big bang theory, which denies God the credit for creating the world, serves as an illustration. Another example is the erroneous notion held by certain Jews that one cannot be
born again unless they have had physical circumcision. All things old, including human customs and philosophies, perish when a person is born again (2 Corinthians 5:17). The believer in Christ must adopt both God’s culture as revealed in the scriptures and God’s Word. The Bible instructs you on how to have a virtuous and successful life that is free from spiritual slavery. As John cautions in his epistles, we should be wary of the Gnostic Gospels. The Social Gospel may seem enticing, but it is not the Saving Gospel, and the outcome will be horrifying. A person can only enter heaven by accepting the Saving Gospel.

PRAYER
Save me from all forms of deception that I may not lose sight of heaven.

BIBLE READINGS: Colossians 2:1-10

Ẹ MÁA KIYESARA

IRUGBIN NAA
Ẹ máa kíyèsara ki ẹnikẹni ki o ma ṣe fí ìmọ ẹtan asán dì yín ní igbèkun, gẹgẹ bí ìtàn eniyan, gẹgẹ bí ipilẹṣẹ ẹkọ ayé, tí kìí ṣe bi ti Kristi. Kólóse 2:8

Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù kìlọ̀ fún ìjọ Kólósè nípa ètò àwọn ọ̀tá láti mú wọn padà sínú ẹwọn rẹ̀. Satani pinnu láti ṣàṣeparí èyí nípasẹ̀ ìmọ̀ ọgbọ́n orí àti ẹ̀tàn; nípa àṣà àti àwọn ìlànà ayé. Ilana ti
awọn ọta ati ti alába-ṣiṣẹ-pọ̀ rẹ ti o jẹ òkúkù, wọn sí tun wá ni ipa loni. O ti ṣafikun awọn koko-ọrọ ati awọn iṣẹ ikẹkọ si eto-ẹkọ ti o ni ero lati mu abuku ba igbagbọ wa. Ìkan nínú àwọn ẹkọ búburú yí ni o takò pé Ọlọ́run ní o da ayé, eyi jẹ àpẹẹrẹ. Àpẹẹrẹ miran ni èrò òdì ti awọn Jù ni wipe kó sì ẹnití o le dì atunbi afi tí o ba ní ikọla tí ará. Gbogbo àwọn ohun àtijọ, pẹlu awọn aṣa awọn eniyan, ati ogbọn ori, awọn nkan wọnyi ni o máà npa rẹ nigbati a ba di atunbi. (2Korinti 5:17). Awọn onigbagbọ ninu Kristi gbọdọ gba ìmọ Ọlọrun ti a fi hàn nínú ìwé mímọ àti ọrọ Ọlọrun. Bíbélì fi ye wá bi a ti ṣe lè ní ìgbé ayé ti o ni ìwà rere àti àṣeyọrí tí kò sí ní abẹ́ isinru ti ẹmi. Gẹgẹ bí Jòhánù àpọsítélì ṣe fí yé wá nínú episteli rẹ pé kí a kíyèsara lọdọ awọn ti gba ẹkọ òdì. Awọn ẹkọ Igbalode máa ni àwọn Itanjẹ ti o nfa ni mọra, ṣùgbọn wọn kì í ṣe ihinrere ti o ní ìgbàlà, abajade rẹ a sì burú jọjọ. Ọna tí ènìyàn lè fi wọ ìjọba ọrùn ni gbigba ihinrere ti o ni ìgbàlà.

ADURA
Gbà mí kúrò lọ́wọ́ gbogbo Itanjẹ ti yíó mú mí padànu ìjọba ọrùn. Amin

BIBELI KIKA: 2 Kolose 2: 1-10

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *