The Turning Point

THE SEED
Thou hast turned for me my mourning into dancing… Psalms 30:11

A turning point is the moment when a significant shift, typically for the better, takes place. In the Bible, there are stories of people, families, and nations that reached a turning
point—a period when events altered for the better. Perhaps you were cast into the pit by Satan. It could be a health, financial, spiritual, or marital pit. Or he has imprisoned you in a financial, marital, spiritual, or physical state. God will use everything Satan has done to your detriment so far for your benefit. God places a great deal of significance on two things: His WORD and His NAME. None of the names that God uses are puns. He cannot ever permit the tainting, demeaning, or mocking of His name. God won’t stand by and permit someone who truly is a
child of God to be accused of putting their trust in God yet failing to be saved (Isaiah 36:18-20). It might be reasonable to inquire if you have reached a turning point in your life toward the God of heaven with everything that is going on in the world right now. Your life is about to take a personal turn, requiring you to make a personal choice to turn your heart, mind, and body toward God and a close relationship with Him. A true desire to find and follow God’s way of life while submitting to Jesus Christ as Lord and Savior, not just an intellectual belief in God.

PRAYER
Oh Lord, turn my life around to the glory of Your name.

BIBLE READINGS: Psalms 30

ÌPELE ÌYÍPADÀ

IRUGBIN NAA
Iwọ ti sọ ìkãnu mí dì ìjọ fún mi… Psalmu 30:11

Akoko iyipada ni akoko igbati iyipada pataki kan ba dé nipato fun iyipada didara julọ ninu Igbesi aye eniyan, igbesi aye ẹbi, igbesi aye ile-iṣẹ tabi igbesi aye orilẹ-ede kan le ni iriri
ilọsiwaju yi. Ninu Bibeli awọn itan awọn eniyan, awọn idile, ati awọn orilẹ-ede wa, ti o de aaye iyipada – akoko kan wa nigbati awọn iṣẹlẹ iyipada fun didara. Bóyá Sátánì sọ ọ́ sínú kòtò tí o lè jẹ́ tí ai ní ìlera, ìnáwó, ẹ̀mí, tàbí kòtò ìgbéyàwó tí o ni idaamu. Tabi o ti fi ọ sinu ẹwọn ìṣúná owo, ti ẹmi tabi ti ara. Ọlọ́run yoo lo gbogbo ohun ti Satani ti ṣe si iparun rẹ titi di isisiyi fun awọn anfani rẹ. Ọlọ́run fi jijẹ́ pàtàkì púpọ̀ sí órí ohun méjì, Ọ̀rọ̀ Rẹ̀ àti Orúkọ Rẹ̀. Ko si ọkan ninu awọn orukọ ti Ọlọrun nlo ti o jẹ ohun amu ṣeré, Ọlọrun Kò lè fàyè gba biba orúkọ Rẹ jẹ, tàbí fífi orúkọ rẹ̀ ṣe ẹfẹ tabi yiyi orukọ Rẹ pada. Ọlọ́run kò ní dúró láti rì í pe wọ́n fẹ̀sùn kan àwọn kan tí wọ́n jẹ́ ọmọ Ọlọ́run nítòótọ́; ti wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run, síbẹ tí wọn kò sì rí ìgbàlà (Isaiah 36:18-20). Ó lè ba ọgbọ́n mu láti béèrè bóyá o ti dé ipò ìyípadà nínú ìgbésí ayé rẹ, sí Ọlọ́run ọ̀run; pẹ̀lú ohun gbogbo tí ń lọ nínú ayé nísinsìnyí. Igbesi aye rẹ ti ṣetan lati ni iyipada ti ara ẹni, to nilo lati yi ọkan, ati ara rẹ si ọdọ Ọlọrun ati ibaṣepọ timọtimọ pẹlu Rẹ. Ifẹ otitọ lati wa ati tẹle ọna igbe aye bí ti Ọlọrun, lakoko ti o fi ara rẹ silẹ fun Jesu Kristi gẹgẹbi Oluwa ati Olugbala, kii ṣe igbagbọ ọgbọn nikan ninu Ọlọrun ni.

ADURA
Gbà mí kúrò lọ́wọ́ gbogbo Itanjẹ ti o le mu mi kùnà orun.

BIBELI KIKA: Kolose 2: 1-10

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *