THE SEED
Whosoever transgresseth, and abideth not in the doctrine of Christ, hath not God. He that abideth in the doctrine of Christ, he hath both the Father and the Son. John 1:9
False teachers try to expand on what Christ taught and add to the truth. If we want to stay away from erroneous doctrine, we must be thoroughly exposed to the genuine doctrine through His words. Knowing the real thing will help you recognise a fake. Anyone who develops the habit of disobeying God’s Word and does not reside in Christ’s teachings is without God and is living a life of disobedience to Christ’s teachings and the Holy Scriptures. Salvation, healing, faith, patience, work, life, death, righteousness, etc. are among the topics covered in our Lord Jesus Christ’s teachings. The books of Matthew, Mark, Luke, and John include these teachings. All have received the Father and the Lord Jesus Christ if they reside in or adhere to these beliefs of Christ. Our ultimate objective is to spread awareness of Christ’s doctrine throughout the entire world, not to showcase our church, our ministries, or our skills or talents.
PRAYER
O Lord, teach me to know more and live in your word, be a disciple of your gospel. Amen.
BIBLE READINGS: John 1:1-10
EKO KRISTI
IRUGBIN NAA
Olukuluku eniti o ba nru ofin ti ko si duro ninu eko Kristi ko gba Olorun, eni ti o ba duro ninu eko on li o gba ati Baba at omo. 2 Johannu 1:9
Awon oluko eke nfe lati fikun oun ti Kristi ko won ati otito. Ti a ba fe lati kuro ninu ilana odi yi, ani lati mo daju eyi ti o je ilana ododo nipase oro re. Ti e ba mo ojulowo, yio je ki e da ayederu mo. Enikeni ti ko ba gbe ninu eko Kristi, o ngbe laisi Olorun, o si ngbe ige aye aigboran si Olorun ati si iwe mimo. Igbala, iwosan, igbagbo, ise, iye, iku, ododo ati be lo ni awon akori eko ti Kristi nkoni. Awon eko yi si wa ninu awon iwe inu majemu titun. Bi e ba gba Baba, ati Jesu Kristi, e o maa tele awon eko wonyi. Oun ti o ye ki a se ni wipe ki a je ki ilana Kristi di mi mo kaakiri agbaye, kiise pe ki a maa polowo ijo tabi ise iranse tabi oun ti a mon se.
ADURA
Oluwa, ko mi lati mo si, ati lati gbe ninu oro re ki nsi je omo lehin ihinrere re. Amin.
BIBELI KIKA: John 1 :1-10