Evil Doers Have No Place With God

THE SEED
“You are not a God who is pleased with wrongdoing; you allow no evil in your presence.” Psalms 5:4 GNBUK

As a child of God, we should not be caught in the web of wrongdoings that will classify us as evil-doers just as the above scripture has expressed. God has no interest in anyone that makes Wrong doing a lifestyle, especially after the truth and salvation have been revealed and received by the individual. The deliberate act of doing wrong is like testing God’s patience. It will put us in a disadvantageous situation where we forfeit God’s presence, it makes us an outcast in our father’s territory and we will live a life that is devoid of divine peace. Beloved of Christ, all that the devil wants for us is to be in the web of wrongdoings to achieve his aim of robbing us of our inheritance through Jesus Christ, an inheritance to be called and known as a child of God who lives a victorious life in doing God’s will.Check your ways today and the life that you are living, if any wrongdoing is found, please work on it and bring yourself back to the presence of God where you should be to connect with your destiny and be a pleasure in His sight.

BIBLE READING: Psalms 5:4-7

PRAYER: Lord Jesus give me the willpower to live above wrongdoings and keep me in your presence always. Amen

AWON ÈNÌYÀN BUBURU KO LE E DURO NÍWAJU OLUWA

IRUGBIN NAA
“Ìwọ kì í ṣe Ọlorun tí inú rẹ̀ dùn sí ìwà àìto; ìwọ kò gba ibi laye níwájú rẹ.” Orin Dafidi 5:4

Gege bí ọmọ Ọlorun, a kò gbodọ̀ wuwa asise ti yio mu ki wọn pewa loni ise ibi gege bi ẹsẹ Ìwé Mímo tí ó wà lókè ti sọ. Ọlọrun ko ni inudidun si ẹnikẹni ti o so iwa ibaje doge paapaa lẹhin ti a ti Fi otitọ ati igbala han, ti onikuluku si ti gba. Ìwà àìto tí a mọ̀omọ̀ ṣe dà bí didan sùúrù Ọlorun wo. Yóò fi wá sínú ipò tí kò já mo nǹkan kan níbi tí a ti pàdánù ifarahan Ọlọrun, yóò sọ wá di ẹni ìtanù ní ìpínlẹ̀ baba wa, a ó sì gbé ìgbésí-ayé tí kò ní àlàáfíà Ọlọrun. Olufẹ Kristi, gbogbo ohun ti Eṣu nfẹ fun wa ni lati wa ninu ahamo iwa asise lati mu ete rẹ se, eyi ti n se gbigba eto wa lodo Jesu Kristi. Ṣayẹwo awọn ọna rẹ loni ati igbesi aye ti o n gbe, ti a ba ri aiṣedede eyikeyi, jọwọ ṣiṣẹ lori rẹ ki o si mu ara rẹ pada si iwaju Ọlọrun nibiti o yẹ ki o wa ni asopọ pẹlu ayanmọ rẹ ki o si jẹ igbadun ni oju Rẹ.

BIBELI KIKA: Iwe Orin Dafidi5:4-7

ADURA: Jesu Oluwa fun mi ni agbara lati bori aisedede, ki o si pa mi mo niwaju Re nigbagbogbo.Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *