Fear Not – You Have Authority Over Them

THE SEED
“And Jesus came and spoke to them, saying, “All authority has been given to Me in heaven and on earth.” Matthew 28:18

Jesus said all powers in heaven and on earth had been given unto him, out of which he gave us the power to trample upon serpents and scorpions and all the powers of the enemy and nothing shall by any means hurt us… (Luke 10:19) Scripture also said, as many that believed in him, to them he gave the power to become the children of God. If we’re children and have been given power, then why should we fear? For there is no power of the devil that is greater than God’s. If we’re Obedient, it is the will of our father to shield us from every attack of the enemy, because God said no weapon fashioned against you shall prosper. So, when the enemy comes raging, do not bat an eyelid, because your father in heaven is in control.

PRAYER
Oh Lord, everything you made that the enemy is putting together to scare me, renders them powerless in Jesus’ mighty name. Amen.
BIBLE READINGS:  2 Cor 10:3-6

  MASE BERU – O Ni ASE LORI WON

IRUGBIN NAA
Jesu si wá, o si ba wọn sorọ, wipe, Aẹ gbogbo li a ti fi fun mi li ọrun ati li aiye. Mátíù 28:18

Jesu sọ pe gbogbo agbara ni ọrun ati lori ilẹ ni a ti fi fun oun, ninu eyiti o ti fun wa ni agbara lati tẹ ejo ati akẽke mọlẹ, ati gbogbo agbara ọta ati pe ko si ohun ti yoo pa wa lara lọnakọna… (Luku 10:19) Iwe-mimọ si wipe, gẹgẹ bi ọpọlọpọ awọn ti o gbà a gbo, awọn li o fi agbara fun lati di ọmọ Ọlọrun. Ti a ba jẹ ọmọ ati pe a ti fun wa ni agbara, lẹhinna kilode ti a o fi bẹru? Nítorí kò sí agbára esu tí ó tóbi ju ti Ọlorun lọ. Bí a bá gbọràn, ìfe baba wa ni láti dáàbò bò wá lowo gbogbo ìkọlù àwọn otá, nítorí Ọlorun sọ pé kò sí ohun ìjà tí a ṣe sí ọ tí yóò pa o Lara. Nítorí náà, nígbà tí otá bá dé, má ṣe berù nítorí baba rẹ tí ń bẹ ní orun ló ń darí rẹ̀.

ADURA
Oluwa, gbogbo nkan t’o se ti ota n ko papo lati deruba mi, so won di alailagbara loruko nla Jesu. Amin.
BIBELI KIKA: 2 Korintin 10:3-6

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *