Fear Not – Your Father Created Them

THE SEED
“I form the light, and create darkness: I make peace and create evil: I the Lord do all these things.” Isaiah 45:7

It is written that the Lord has not given us the spirit of fear, but of power love and a sound mind. Some Christians tend to fear the works of the devil more than they fear God. They often feel threatened by the enemy. When the enemy charges, fear grips them even though they are children of God, they forget that our victory is in the Lord and that we are children of light. By God’s design, He made light superior to darkness. In the scripture above, God reveals to us that he formed light and darkness, he made peace and created evil. The fact that our father in heaven made all things including light and darkness means that he has absolute power and dominion over them and their manifestation. For this reason, we as His children should not be in fear of anything created by God.

PRAYER
Lord help me to build my confidence in you that creates all things and banish the fear of your creations from my heart in Jesus’ name. Amen
BIBLE READINGS:  Isaiah 45:4-7

 MASE BERU – BABA RE NI O DA WON

IRUGBIN NAA
“Emi ni mo da imole, mo si da okunkun: mo da alafia, mo si da ibi: Emi Oluwa li o nse gbogbo nkan wonyi. Aísáyà 45:7

A ti kọ o pé Olúwa kò fún wa ní emí ìberù, bí kò ṣe ti agbára ìfe àti okan tí ó yè kooro. Diẹ ninu awọn Kristiani maa n bẹru awọn iṣẹ esu ju bi wọn se bẹru Ọlọrun lọ. Won maa n berù ihale Otá lopo ìgbà. Nigbati ọta ba ha le, ẹru ba wọn bi o tilẹ jẹ pe wọn jẹ ọmọ Ọlọrun. Wọn gbagbe pe iṣẹgun wa ninu Oluwa ati pe awa jẹ ọmọ imọlẹ. Nipa alakale Ọlọrun, O mu imọlẹ ga ju òkunkun lọ. Ninu iwe-mimọ ti o wa loke, Ọlọrun fi han wa pe o ṣẹda imọlẹ ati òkunkun, o ṣe alafia ati ibi. Òtíto ni wi pé,bàbá wa tí ń bẹ ní orun dá ohun gbogbo títí kan ìmole àti òkùnkùn túmo sí pé ó ní agbára ati isakoso Lori gbogbo wọn pátápátá àti ìfarahàn wọn. Nítorí ìdí èyí, àwa gege bí ọmọ Re kò gbodo máa berù ohunkóhun tí Ọlorun dá.

ADURA
Oluwa ran mi lowo lati Fi igboya mi sinu Iwo ti o da ohun gbogbo, ki o si pa iberu awon ti o da  kuro ninu okan mi ni oruko Jesu. Amin
BIBELI KIKA: Aísáyà 45:4-7

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *