THE SEED
“For God so loved the world that he gave his one and only Son, that whoever believes in him shall not perish but have eternal life.” John 3:16, NIV
Have you at any point contemplated how love affect your giving? I have heard it said that you can give without loving, however you can’t love without giving. Love, God’s love in us, prompts us to give of ourselves — our time, capacities, abilities, time and assets. As a matter of fact, God is love, and the bible lets us know that the world recognizes Christians by their love. That implies the world will recognize us as Christians by our generous, giving hearts. During this Christmas holiday, the season of giving, remember to take time to focus on the greatest gift of all, the gift of eternal life through Jesus. If you’ve never received this gift, I invite you to open your heart and pray this simple prayer: “Lord Jesus, I come to You today, giving You all that I am. I repent of my sins and confess that I need You. I believe You died and rose for me. Be my Lord and Savior and make me new today. I receive Your love and Your gift of eternal life.”
PRAYER
Father, thank You for loving me and setting me free. I choose to serve You with my whole heart all the days of my life. Help me love others the way You love me. Give me opportunities to be a blessing everywhere I go in Jesus’ name. Amen.
BIBLE READINGS: John 3
NITORI ỌLỌRUN FẸ ARÁIYÉ TO BẸ GẸ
IRÚGBÌN NÁÀ
“Nitori Ọlọrun fẹ arayé tobẹ gẹ, ti o fí Ọmọ bíbí rẹ kanṣoṣo fúnni, kí ẹnikẹ́ni tí o bá gbà á gbọ má bà ṣegbé, ṣugbọn kí o le ní ìyè àìnípẹkun.” Johannu 3:16
Njẹ o tí fí igba kàn ro o bi ifẹ ṣe ni ipapọ pẹlu fifunni? Mo ti gbọ ri tí a sọ pé o lè fún ní li ẹbùn, la i fẹràn eniyan ti o fún l’ẹbun Bi o tí wù kí o rí o kò lè fún ní l’ẹbun la i jẹ pé o fẹràn irú ẹni bẹẹ. Ìfẹ Ọlọrun ninu wá máa nrú wa sókè láti fún ní, ni akoko wa, agbara wa, ipá wa ati awọn ohun tí a bá ní. Otitọ ọrọ naa ní pe ifẹ ni Ọlọrun bíbélì jẹ kí aráyé mọ àwọn Kristẹni nipa ìfẹ wọn. Eleyi tumọ si pe ayé yíó rí wa bi Kristẹni, nipa fifi ọkan wa fún ní tinutinu. Ni akoko ọdún Kérésìmesì tí o jẹ àsìkò fi fún ní li ẹbùn, a gbọdọ rántí ẹbùn tí o tóbi julọ; ẹbùn ayérayé nipasẹ Kristi Jésù. Tí o kò bá tí ì gbà ẹbùn yí, mo pé ọ láti ṣi ọkàn rẹ̀ ati lati gba adura tí o rọrun yi: Oluwa wa Jesu, mo wa loni, lati fún ọ ní ohun gbogbo ti mo jẹ. Mo ronu piwada awọn ẹṣẹ mí ati pe mo jẹwọ pe mo nilo yin. Mo gbagbọ wípé o kú o sì tún ji dìde fún mi. Jẹ, Olúwa àti Olùgbàlà mí sọ mi di títún lóni. Mo gba ìfẹ Rẹ ati ẹbùn ayérayé.
ÁDÙRÁ
Baba Mo dupẹ ti ẹ fẹmi ti ẹ sì tún tù mí sílẹ̀. Mo Yan lati sìn ọ pẹlu gbogbo ọkan mi ní gbogbo ọjọ ayé mi. Ranmilọwọ lati feran awọn ẹlomiran bi O ti fẹ mi. Fún mí ni anfaani lati jẹ ẹni tí o nbukun fun ni, ni ibi gbogbo ti mo ba nlọ ní orúkọ Jésù Àmín.
BIBELI KIKA: Johannu 3