“Now therefore, if you will indeed obey My voice and keep My covenant, then you shall be a special treasure to Me above all people; for all the earth is Mine.” — Exodus 19:5 NKJV
Every child of God carries a divine deposit— a treasure that must shine in a dark and troubled world. As God’s light, we must obey His voice, reflect His love, and walk in integrity. A city set on a hill cannot be hidden, and neither should our lives be hidden. Being an uncommon treasure means becoming a vessel of blessing: bringing joy, peace, and solutions wherever we go, just as Jesus went about doing good. To remain God’s special treasure, obedience must be paramount, even when it is costly.
BIBLE READINGS: Matthew 5:13–16
PRAYER: My Father and King, thank You for Your grace. Help me to live as Your special treasure and shine Your light in the world. Amen.
OHUN ÌNÍ ỌLỌ́RUN TÍ Ó JẸ́ PÀTÀKÌ IRUGBIN NAA
“Njẹ nísinsìnyí, bí ẹ̀yìn ba fẹ́ gba ohun mí gbọ nitootọ, tí ẹ ó sì pa májẹ̀mú mi mọ́, nigbana lí ẹ̀yìn ó jẹ́ ìṣúra fún mí jù gbogbo eniyan lọ: nítorí gbogbo àyè ní ti emi” Ẹ́KÍSÓDÙ 19:5.
Gbogbo ọmọ Ọlọrun ní o ni ohun ìmúṣogo atoke wá–ohun iṣura ti o gbọdọ tàn ninu òkùnkùn àti wahala aye. Gẹ́gẹ́ bí ìmọ́lẹ̀ Ọlọ́run, a gbọ́dọ̀ ṣè igbọràn sí ohùn Rẹ̀, fi ìfẹ́ Rẹ̀ hàn, kí a sì rìn ní ìdúróṣinṣin àti ìjẹ olotitọ. Ilu ti a tẹ̀dó lori oke ko le farapamọ, bẹni ko yẹ ki ẹmi wa farasin. Jíjẹ́ ìṣúra tí kò wọ pọ; túmọ̀ sí jí jẹ́ ohun èlò ìbùkún: mí mú ayọ̀, àlàáfíà, àti àbájáde wá níbikíbi tí a bá lọ, gẹ́gẹ́ bí Jésù ṣe máa nṣe oore kiri. Láti jẹ́ ohun ìṣúra pàtàkì, ìgbọràn jẹ́ dandan bi o ti wu ki o lágbára to.
BIBELI KIKA: Mátíù 5:13–16
ADURA: Baba ati Oba mi, e se fun Ore-ofe Yin. Ran mi lowo lati gbe gege bi isura pataki Re ki o si tan imole Re si aye. Amin.