Great Man Of War (God)

THE SEED
“The Lord is a man of war: the LORD is His Name.” Exodus 15:3

You are Jehovah, You are the Mighty Man in Battle. You are Jehovah, you are the Mighty Man of War. Oh, You are Jehovah. We have a Father that will never fail us, He doesn’t sleep nor slumber over His children. That is why when we dwell in His secret place, and abide under His shadow, He fights and wins our battles for us. He cannot trade us for less. So many promises God made with us concerning the battles we wrestle with each day, even the ones He Conquer for us without our knowledge are more than those we know or see. The Lord shall fight for you, and ye shall hold your peace (Exodus 14 : 14 KJV). Another says, Nay, in all these things we are more than conquerors through Him that loved us (Romans 8 : 37). Psalm 44 : 5 KJV. Through thee we will push down our enemies: through thy Name will we tread them under, that rise up against us. From Isaiah 42 : 13, The Lord shall go forth as a Mighty Man, he shall stir up jealousy like a Man of war: He shall cry, yea, roar; He shall prevail against His enemies, Jeremiah 1 : 8 too says; Be not afraid of their faces: for I am with thee to deliver thee, and whatever I command thee, thou shalt speak.

BIBLE READING: Psalm 24:7-10

PRAYER: God, fight all our battles for us where we know and we don’t know in Jesus Mighty Name.

OKUNRIN NLA OGUN (OLORUN)

IRUGBIN NAA
Ologun ni Oluwa, Olúwa ni orúkọ Re. Eksodu. 15:3.

Ìwọ ni Jèhófà, Ìwọ ni Alágbára Ńlá Nínú Ogun. Ìwọ ni Jèhófà, ìwọ ni Alágbára nla loju ogun, ìwọ ni Jèhófà. A ni Baba ti ki yio ja wa kule laelae. K‘o sun beni ko toogbe Lori awon omo Re. Ìdí nìyí tí a bá ń gbé ní ibi ìkoko re, tí a sì dúró lábẹ́ òjìji re, yóò jà, yio sì ṣegun fún wa. Ko le ṣoun yepere fun wa. Opolọpo ìlérí tí Ọlorun ṣe nípa àwọn ogun tí a ń jà lójoojúmo, àní àwọn tí Ó ṣegun fún wa ti a ko mo Poju eyi ti a foju ri lo. Oluwa yio jà fun nyin, ẹnyin o si ni alafia(Eksodu 14:14). Òmíràn wí pé, Beekoo, nínú gbogbo nǹkan wonyí awa ju aṣegun lọ nípase ẹni tí ó fe wa (Romu 8:37). Iwe Orin Dafidi 44:5 . Nipasẹ rẹ li awa o fi le awọn ọta wa: nipa orukọ rẹ li awa o tewọn mọlẹ, ti o dide si wa. Lati Isaiah 42:13, Oluwa yio jade bi Alagbara, yio ru owú soke bi jagunjagun: yio kigbe, nitõtọ, ramuramu; Yio si bori awon ota Re, Jeremiah 1:8 pelu wipe; Máṣe bẹru oju wọn: nitori emi wà pẹlu rẹ lati gbà ọ, ati ohunkohun ti mo ba palaṣẹ fun ọ, ni ki iwọ ki o ma sọ.

BIBELI KIKA: Iwe Orin Dafidi 24:7-10

ADURA: Olorun, ja gbogbo ogun wa fun wa nibiti a ti mo ati ti a ko mo ni oruko Jesu Alagbara.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *