In God’s Will

                                                       IN GOD’S WILL
THE SEED
“”For My thoughts are not your thoughts, Nor are your ways My ways,” says the LORD.”
Isaiah 55:8 NKJV
Our God is all knowing God. He knows all things; He can do all things. He knows the end
from the beginning. His thoughts towards us are peaceful and not evil. His plans for us are
good. Everyone will be successful at what they do if we can know the end from the beginning.
The bible says, there is a way that seems right before men, but the end thereof is
destruction. Many times, our judgments are affected by things we can see and hear now, but
God is omniscient and all knowing, He knows what is good for us.
Before I got married, I wanted two boys as children, but when I got married and my wife
got pregnant, our first child turned out to be a girl. I believed that the second one would be a
boy, but I was blessed with another girl! Then I made up my mind to not have another baby.
Then the Lord told me that He did it according to His will and that my prince will come. Then I remembered the word of God that says’ Woe to him that strives with his maker’ Isaiah 45:9.
Behold, at the third attempt, the boy came according to the word of God. Great is His
faithfulness. He is ever faithful, He never fails. However, His will is the best for us. Let us learn
to seek His will for us; therein lies our glory, destiny, and purpose in life.
PRAYER
Oh Lord, give me the spirit to remain in Your will till the end in all endeavours of my life. Amen
BIBLE READINGS: Hebrews 13:20-21
                                                       NÍNÚ ÌFẸ OLUWA
IRÚGBÌN NÁÀ
“Nitori èrò mi kìí ise ero nyìn, bẹẹ ni ọnà nyìn kí iṣe ọnà Mí, li Oluwa wí.” Isaiah 55:8
Ọlọrun wà jẹ enití o ni ìmọ̀, o mọ ohun gbogbo, o sí lè ṣe ohun gbogbo. O mọ òpin lati
ibẹrẹ, èrò Rẹ sí wá jẹ alaafia; kìí ṣe ti ìbí, rere ní eto rẹ fún wa. Onikaluku eniyan ní yíó ni aseyori nínú ohun tí wọ́n nṣe, tí a bá ní ipá lati mọ igbehin lati ibẹrẹ.
Bíbélì sọ pé ọnà kan wà tí o tọ l’oju eniyan ṣugbọn òpin rẹ ibi ní. Ọpọ igba ní àwọn idajọ
wa, a máa ní idiwọ nípa ohun tí a ngbọ́, tabi tí a nrí nisisiyi. Sugbọn Ọlọrun jẹ oni imọ, o mọ
ohun gbogbo, O mọ ohun ti o dára fún wá.
Kí nto gbeyawo, ohun tí ọkàn mi nfẹ ni pe ki nkọkọ ni ọmọ ọkunrin méjì. Lẹhin igbeyawo
yí, iyawo mi ní oyún, akọbi wá jẹ ọmọ obirin. Mo ni ìgbàgbọ pé ọmọ Kejì yíó jẹ ọmọ ọkunrin.
Sugbọn a fí ọmọ obirin miran damilola! Mo sì mú ìpinnu pe nkó bí ọmọ míràn mọ.
Oluwa wá sọ fún mi pé òun ṣe èyí, nínú ìfẹ oun ní; wipe ọmọ ọkunrin nbọ. Mo sì rántí
ọrọ Olọrun ti o sọ pé “Egbe ní fún ẹnití o bá ẹlẹdà rẹ já. (Isaiah 45:9). Oyún ele keta dé gẹgẹ bí ọrọ Ọlọrun, a sì fi bi ọmọ ọkunrin. Títóbi ní òtítọ Rẹ, olotitọ ni titi lailai. Kìí jani kule, ìfẹ Rẹ ni o dára jù fún wá. É jékí a kọ lati máa ṣafẹri ìfẹ Rẹ, fún wa, nipa ṣiṣe eyi ni ògo, ayanmọ atí ẹtọ Rẹ wà fún wá.
ADURA
Oluwa fún mi ni èmí tí o dúró nínú ìfẹ Rẹ titi dopin, ninu ila kọja mi lójó ayé mi. Amin.
BIBELI KIKA: Heberu 13: 20-22

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *