JEALOUSY

                                                               JEALOUSY

THE SEED

“For where envying and strife is, there is confusion and every evil work.” James. 3: 16 KJV

Jealousy is something that many people experience. jealousy can occur during any part of one’s spiritual journey. When you do things with pure intentions, order and positivity will overflow from your life. Jealousy is the rage of a man. Jealousy may sneak up on you, but with God it can be eliminated. The Bible says wrath is cruel and anger is outrageous, but who is able to stand before envy? Jealousy can be so destructive, both spiritually, emotionally and relationally. it can literally feed one to murder. Jealousy is that sneaky sin that comes upon us unexpectedly. When you are jealous, you will be eager to obtain something that you don’t have, and it will lead to covetousness and idolatry. Jealousy is a sinful act, it comes from the flesh and it needs to be confessed and repented. If you are not content with what you have you will definitely become jealous of others in possession of your wishlist. Our God is a jealous God who does not want us to have any other god except him. He wants us to repent from our sinful ways and give glory to him alone. Out of jealousy, Saul wanted to kill David because he defeated Goliath and brought the Israelites to victory. Don’t allow jealousy to consume you and also determine your identity and happiness. The root cause of jealousy and envy are connected to a person’s inability to see what God has provided in their life and a lack of thankfulness.

Therefore, stop being jealous,It is a bad spirit that can lead you to hell.

BIBLE READING: Galatians 5: 16 – 26

PRAYER: Lord Jesus, my sincere desire is to become holy like you, set me free from anxious thoughts that cause me not to become jealous towards others in Jesus name. Amen.

                                                               OWU

IRUGBIN NAA

“Nitori ibiti owu ati ija ba gbe wa, nibe ni rudurudu ati ise buburu gbogbo wa.” Jakobu 3:13

Owu je ohun ti o nse opolopo eniyan, owu le jeyo ni onakona ninu irin ajo igbagbo eda.nigba ti o ba se ohun pelu inu mimo, eto, iserere yio po ninu aye re. owu ni ibinu ti eniyan ko lee pamora ni ojo esan. Owu le gbeni wo sugbon ninu Olorun, o le di ohun igbagbe. Iwe mimo wipe, ibinu ni ika, irunu si ni kikun omi, sugbon tani yio duro niwaju owu? Owu le ba nkan je. Nipa ti ara ati nipa ibasepo pelu eniyan. Eyi a maa fa ipaniyan. Owu je ese ti o maa n dede gbeni wo lairotele. Nigba ti o ba njowu, wa maa lepa lati wa ohun ti o ko ni, yio si jasi ojukokoro ati iborisa. Ese ni owu jije, eran ara ni o maa n faa, a ni lati jewo re ki a si ronupiwada. Bi o ko ba ni itelorun pelu ohun ti o ni, dandan ni ki o jowu awon ti o ni. Olorun owu ni Olorun wa, ko fe ki a ni Olorun miran lehin On. O fe ki a ronupiwada kuro ninu gbogbo ese wa ki a si fi ogo fun On nikan. Nitori owu ni Saulu se fe pa Dafidi nitoriti o segun Goliati, o si mu isreali segun. Mase fi aye sile ki owu ki o di orisa ti yio je o run, tabi ti yio so idanimo ati idunnu re. ohun ti n fa owu ati ilara ni aile maa wo ohun ti olorun ti se ninu aye eni ati aimoore. Bi o ba njowu, waa maa beru ki o mase so ipo re nu fun elomiran. Nitorinaa, dekun owu jije, emi buburu ni, o si le ran o lo si orun apaadi.

BIBELI KIKA: Galatia 5:16-26

ADURA: Jesu Oluwa, ohun ti o wu mi julo ni lati je mimo bii tire, gba mi lowo ero pupo to maa n mu mi jowu awon elomiran ni oruko Jesu. Amin

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *