Jesus Is Alive And Active

THE SEED
By this will we have been sanctified through the offering of the body of Jesus Christ once for all. Hebrews 10:10

Have you ever questioned what Jesus is doing in paradise now? He is seated at God’s right hand, according to today’s verse. We could question what He’s doing up there as a result. Is He only anticipating His return to the earth? No! He genuinely does a lot of work for us. First, the Holy Spirit, who is the embodiment of the Lord Jesus, resides within every believer (John 15:26; Romans 8:9-10). This implies that Christ is forming your character and enhancing your obedience from heaven. Second, the Lord pleads our case (Hebrews 7:25). He petitions the Father on our behalf and delivers our prayers. Third, Jesus serves as our defender when we sin, as shown in 1 John 2:1–2. Because of His sacrifice and our confidence in Him, He stands in the way between us and the Father and declares our righteousness. Finally, Christ is setting everything in motion for His second coming and preparing a home for us in heaven (John 14:1-3). Jesus is carrying out the Father’s will in heaven. And here on earth, we ought to follow suit. When we emulate the Lord’s life in our actions, attitudes, words, and behaviour, He can save people through us. Let us serve as a beacon for Christ by serving as His feet, hands, voice, eyes, and ears.

PRAYER
Thank God for Jesus is alive and active in my life and family
BIBLE READINGS:  Hebrews 10:10-14

JESU N BẸ LAAYE, O SI N SIṢÉ

IRUGBIN NAA
Nípa ìfẹ́ náà ni a ti sọ wá di mímọ́  ipa ẹbọ ti Jesu Kristi fi ara rẹ̀ rú lẹ́ẹ̀kan oo – Heberu 10:10

Nje o tilẹ ti ro ohun ti Jesu nṣe ni ọrun bayii? Ó n bẹ ni apa otun Oluwa lori itẹ. O ṣeeṣe ki a ma bere ohun ti o tilẹ nṣe. Njẹ o tilẹ n duro titi yio fi pada bo wa saye ni? Rara o, iṣẹ ti O nṣe ko kere rara. Ni akọkọ, Ẹmi Mimọ ti nṣe agbewo Kristi n gbe ninu gbogbo onigbagbọ tootọ. Eyi tumọ si wipe Oluwa n dá ọ ni iwa rere Ó si n mu ọ dagba si ninu igboran. Ekeji, Oluwa n bẹbẹ fun wa ni ọdọ Olorun (Heberu 7:25), O si n mu ebe adura wa tọ Oluwa. Ẹkẹta, Jesu je alagbawi fun wa nigbati a ba deṣẹ gẹgẹ bi a ti kọ sinu iwe 1 John 2:1-2. Nitori ẹbọ Rẹ ati igbagbo wa ninu Rẹ, Jesu je alarina laarin awa ati Olorun, Ó si n sọ ododo wa. Laakotan, Jesu n mura silẹ fun ipadabọ Rẹ, o si n pese aye silẹ fun wa ni ọrun (Johannu 14:1-3). Jesu n ṣe ifẹ Baba Rẹ ni ọrun, awa naa si gbọdọ ṣe ife Rẹ ni aye. A gbọdọ dabi tirẹ ninu iwa, ọrọ ati iṣesi wa. O le ti ọwọ w agba awon eniyan la. Ẹ jẹ ki a je imọle Kristi nipa jijẹ ọwọ, ẹsẹ, oju, eti ati ohun fun un.

ADURA
Mo dupẹ Oluwa nitori Jesu wa laaye, O si n ṣiṣẹ ninu aye emi at ẹbi mi.
BIBELI KIKA: Heberu 10:10-14

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *