JUST DO IT

JUST DO IT

THE SEED

“And Abraham rose early in the morning, and saddled his ass, and took two of his young men with him, and Isaac his son, and claved the wood for the burnt offering, and rose, and went unto the place of which God had told him.” Genesis 22: 3 KJV

I am sure you are familiar with the slogan ‘Just do it’ made popular by sportswear manufacturer, Nike. The idea is that you are invited to stop putting off doing sport and exercise. Stop looking for excuses, stop procrastinating, stop dilly-dallying; as they say in England. Get up, and just do it. Well, this motto accurately describes Abraham’s life. He didn’t wait around to think about the Lord’s instructions. Whether it made sense to him or not, he just did it. In this instance, he got up early in the morning the next day and did what God told him to do. Sometimes, God’s instructions can sound like foolishness to the natural mind (I am very sure Abraham didn’t tell Sarah, he was going to sacrifice Isaac). But be assured that God will never tell you to do something contrary to His word. God will not lead you to break the law, or take something that does not belong to you. Sometimes when I hear believers give testimonies of an instruction they received from God, the length of time between when they knew God wanted them to do something, and the time they did that thing, can span weeks or even months. This includes me. Why do we delay carrying out God’s instructions? Why do we sit and think about His commands, instead of obeying them instantly? Next time you hear Him or sense His leading clearly; when you know what God wants you to do; don’t put it off. Don’t procrastinate, don’t delay, don’t dilly-dally, … just do it.

BIBLE READING: Genesis 22:1-3

PRAYER: Heavenly Father, from today, I want to stop delaying the obedience of your instructions. Help me in Jesus name. Amen.

 

 

SÁ TÍ ṢÉ É

IRUGBIN NAA

“Abrahamu sí dídé ní kùtùkùtù òwúrọ, o si di kẹtẹ kẹtẹ rẹ̀ ní gàárì, o si mu méjì nínú àwọn ọ̀dọ̀-mọkùnrin rẹ̀ pẹ̀lú rẹ̀, ati Ísáákì, ọmọ rẹ̀ o si la igi fún ẹbọ sísun náà, o si dìde, o sí lọ sí ibi ti Ọlọ́run sọ fún un.” Genesisi 22:3.

O da mi loju pe a ti gbọ bi a ti máa nsọ ọ̀rọ̀ kàn pé “ṢA TI ṢÉ E” èyí jẹ ki ọ̀rọ̀ yi jẹ́ gbajumọ nínú aṣọ oṣere ti a ṣe lati ọwọ́ “NIKE” ti o jẹ́ oluṣé aṣọ naa. Ohun tí o wà ni idi ọ̀rọ̀ yí ni pé, a pe wá lati ma dẹkùn ṣíṣe ere idaraya. Dẹkùn ṣíṣe awawi, fi òpin sí, sí sun eré idaraya di ọjọ́ ọ̀la, dẹkùn ìwà kò ṣeku- kò ṣeye (dilly- dallying) bi nwọn ti sọ ni ìlú-ọba.  Dide ki o ṣa ti ṣe!

Gbolohun ọrọ yi ṣe apejuwe ilé aiye Ábúráhámù dáradára. Kò duro ni ayika lati ro nipa itọsọna Olúwà. Boya o mu ọgbọ́n dání lójú rẹ̀ tàbí bẹ kọ, o kan ṣe e. Nínú àpẹẹrẹ yìí, ó dìde ní kùtùkùtù òwúrọ̀ ọjọ́ kejì ó sì ṣe ohun tí Ọlọ́run ní kó ṣe. Nígbà míràn ìlànà Ọlọ́run lè dà bí ìwà òmùgọ̀ sí Ẹ̀dá ènìyàn (ó dá mi lójú pé Ábúráhámù kò sọ fún Sárà pé òun yió fi Ísákì rúbọ) Ṣùgbọ́n kí ó dá ọ lójú pé Ọlọ́run kò ní sọ fún ọ pé kí o ṣe ohun tó lòdì sí ọ̀rọ̀ rẹ̀. Ọlọ́run kò ní tọ ọ láti rú òfin, tàbí kí o mú, ohun kan tí kì í ṣe tirẹ̀. Nigbakugba ti mo ba gbọ ti àwọn onigbagbọ ńsọ nípa ẹri ẹkọ ti wọn gba lati ọdọ Ọlọrun, akoko laarin igba ti wọn mọ pe Ọlọrun fẹ ki wọn ṣe ohun kan, ati àkókò ìgbà tí wọ́n ṣé ohun náà le gba wọn ni ọsẹ tabi awọn oṣù. Eyi kò yọ èmi náà silẹ mi. Kínì idí ti a fi ń fà sẹ́yìn láti tẹ̀ lé ìtọ́ni Ọlọ́run? Kilode ti a fi joko ki a ronu nipa awon àṣẹ Rẹ̀, dipo ki a gbọràn si wọ́n lẹsẹkẹsẹ. Nigba miran ti o ba gbọ ohun Rẹ̀ tabi ri ẹ̀ri idari kedere;  nigbati o ba mọ ohun ti Ọlọrun fẹ ki o ṣe;  maṣe fi silẹ. Maṣe fi da ọ̀la, ma ṣe ìjàfará, maṣe hùwà ko ṣé ku ko ṣeye (dilly-dallying) tilẹ̀ ṣe e.

BIBELI KIKA: Genesisi 22 : 1-3

ADURA: Baba ọrun, lati oni lọ, Mo fẹ fi òpin si ìlọ́ra lati ṣe ìgbọràn sí àwọn ìlànà Rẹ. Ran mi lọ́wọ́ ni orúkọ Jesu. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *