MIGHTY WARRIOR

THE SEED

“But the Lord is with me as a mighty terrible one: therefore my persecutors shall stumble, and they shall not prevail: they shall be greatly ashamed; for they shall not prosper: their everlasting confusion shall never be forgotten.” – Jeremiah 20:11 (KJV)

As God’s children, opposition and persecution are inevitable. The devil and his agents will always contend with those walking in God’s light. But we have the assurance that our God is a mighty warrior who fights for His people. He fought for Israel at the Red Sea, defended Daniel in the lions’ den, and protected the Hebrew boys in the fiery furnace. He will also fight for you. When you live in faith and walk closely with Him, His hedge of protection remains unbroken.

 

BIBLE READINGS:  Exodus 14:13–20 (KJV)

PRAYER: My God and Defender, arise as a mighty warrior in my life. Let every enemy of my destiny stumble and fall, in Jesus’ name. Amen.

 

AKONI OGUN

IRUGBIN NAA

Ṣugbọn Oluwa mbẹ lọdọ mi bi akọni ẹlẹrù, nitorina awọn ti nṣe inunibini si mi yio ṣubu, nwọn kì yio le bori: oju yio tì wọn gidigidi, nitoripe nwọn kì o ṣe rere: a ki yio gbagbe itiju wọn lailai! Jeremiah 20:11

 

Gege bi omo Olorun, a ko le sai ri atako ati inunibini. Esu ati awon omo ogun re maa n koju ija si awon ti nrin ninu imole Olorun. Sugbon, a ni idaniloju wipe, akoni ogun ni Olorun wa, ti nja fun awon eniyan Re. O ja fun Israeli leti okun pupa, O pa Danieli mo ninu iho kiniun, o yo awon omokunrin Heberu meta, ninu ina ileru, Yio ja fun iwo naa pelu. Nigbati o ba ngbe ninu igbagbo, ti o si nba rin, odi abo Re ko le wo.

 

BIBELI KIKA: Eksodu 14:13-20

ADURA: Olorun ati Olugbeja mi, dide gege bi akoni ogun ninu aye mi, je ki gbogbo awon ota ayanmo mi, ki won kose, ki won si subu, ni Oruko Jesu. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *