THE SEED
“O taste and see that the Lord is good: blessed is the man that trusteth in him.” – Psalm 34:8 (KJV)
To truly experience God’s goodness, believers must cultivate a close relationship with Him. His blessings—protection, provision, healing, and victory—are for those who trust in Him fully. As we walk with God through prayer, obedience, and the study of His Word, we become more aware of His unfailing love and power. Trusting God in challenging times assures us of His presence and deliverance. As Isaiah 43:2 affirms, even when we pass through the waters, God is with us. A heart of gratitude and a lifestyle of faith enable us to continually taste and see His goodness.
BIBLE READINGS: Psalm 34:1–10 (KJV)
PRAYER: Almighty God, grant me the grace to trust You completely and to continually enjoy the sweetness of Your goodness, in Jesus’ name. Amen.
TITO OORE OLORUN WO
IRUGBIN NAA
Tọ́ ọ wò, ki o si ri pe, rere ni Oluwa: alabukún fun li ọkunrin na ti o gbẹkẹle e. Orin Dafidi 34:8
Ki a le je alabapin ore Olorun nitoto, onigbagbo gbodo sunmo Olorun, ki o ni ibasepo ti o dara pelu Re. Ibukun, abo, ipese, iwosan ati isegun Re wa fun awon to gbekele E patapata. Bi a ti nba Olorun rin ninu adura, igboran, ati ninu kiko eko Oro Re, a o tubo mo ife Re ti ki janikule ati agbara Re. Gbigbekele Olorun ni akoko ipenija maa n fun wa ni idaniloju iwalaaye ati itusile Re. Gege bi Iwe Isaiah 43:2 ti fi idi re mule wipe, nigbati a ba tile nla omi koja, Oluwa wa pelu wa. Okan ope ati igbe aye igbagbo maa nfun wa ni anfani lati to ore Olorun wo nigba de igba, ki a si ro Ore Re.
BIBELI KIKA: Orin Dafidi 34:1-10
ADURA: Olorun Alagbara, fun mi ni ore-ofe lati gbekele o patapata, ki nle maa je adun ore Re nigba de igba, ni Oruko Jesu. Amin