Place It At The Foot Of The Cross

THE SEED
“You will keep him in perfect peace, whose mind is stayed on You, because he trusts in You.” Is 26:3

Jesus didn’t die on the cross so He could judge us. He came to save us and award us the peace that outperforms understanding as we explore life to the baffling brilliant qualities of heaven. The portion of what we will see upon our eagerly awaited appearance has not entered our brains. However, until that day when we meet our Saviour eye to eye, we should keep on finishing what has been started. We were never guaranteed a bed of rose on this planet. We were, notwithstanding,
guaranteed that in Him we could discover a genuine sense of harmony. Jesus will worry about our concerns regardless of how extraordinary our load is and make a way where none is by all accounts. He knows our end all along. What is it that you really want to entrust Him with today? Take it to the foot of the cross and leave it there. Try not to convey a contributor to the issue back home with you. Leave the whole weight with God, realizing that He won’t just address your issue but also give you sweet rest in the valley.

PRAYER
Lord I come unto your throne of mercy. Lift the burden of my life, that I may find peace in you Amen
BIBLE READINGS: Matthew 11: 28-30

GBE SI ESE AGBELEBU

IRUGBIN NAA
“Iwo o paa mo li alaafia pipe, okan eniti o simi le o, nitoriti o gbekele o.” Isaiah 26:3

Jesu ko ku lori igi agbelebu ki o baa le dawa lejo, o wa lati gba wa la, ki o si fun wa ni alaafia ti o tayo oye eniyan, eyi ti a o fi gbe ninu aye titi ao fi ri ogo alailegbe ti orun. Ero ipin ohun ti a o ri nigba ti a ba de ibi ti a o ti farahan, ko tii si ninu okan wa. Wayi, titi di ojo naa, ti a o ri Olugbala wa loju koju, e je ki a maa se aseyori ohun ti ati bere. Olorun ko se ileri fun wa wipe a ko ni ri isoro laye, sugbon ninu re ni a ni irepo otito. Jesu a maa bawa gbe eru wa fuye bi o tile wu ki o wuwo to, yio si la ona nibiti ona ko si. O mo opin wa lati ibere. Kini ohun naa ti o fe ko lee lowo loni? Gbe e lo si ibi ese agbelebu ki o si fi sile sibe. Gbiyanju ki o mase gbe ohun to nise pelu isoro naa pada sile pelu re, fi gbogbo re sile lodo Olorun, ki o si mo wipe ko ni yanju isoro re nikan, sugbon yio tun fun o ni isinmi didun ni petele.

ADURA
Oluwa, mo wa si ibi ite aanu re, gbe isoro aye mi fo, ki n le ni alaafia ninu re. Amin.
BIBELI KIKA: Matteu 11: 28-30

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *