POWER OF AGREEMENT THE SEED
MAY 5 THU 2022
“And they overcame him by the blood of the Lamb, and by the word of their testimony…” Rev. 12: 11 KJV
Everything in life needs your agreement. The Word and power of God needs your agreement to work for you. Even the devil needs your agreement to come into your life and wreak havoc.
This may sound funny to hear, but when you refuse to resist the devil, you are agreeing with him.
Our text above tells us that the blood of Jesus is sufficient to work for you but not without your agreement. You and I are required to give agreement to it by declaring and testifying to the truth of God’s word and what the blood stands for.
Therefore, resist every negative thought, picture or report, and declare what God says about the situation instead.
Resist, even if you have to do it till the very end. This is the only way we overcome the enemy of our progress.
PRAYER
Heavenly Father help me to always remember to declare Your truth in the face of every adverse circumstance I face, in Jesus name Amen.
BIBLE READINGS: Genesis 11: 1-9
AGBARA IFOHUNSOKAN
IRUGBIN NAA
Nwon si segun re nitori eje Odo-Agutan naa, ati nitori oro eri won, nwon ko si feran emi won ani titi de iku. Ifihan 12:11
Ohun gbogbo laye lo nilo ifohunsokan re. Oro ati agbara Olorun nilo ifohunsokan re ki won to sise fun o. esu paapaa nilo ifohunsokan re lati wo inu aye re ki o si se ose. Eleyi le dun bakan leti sugbon bi o ba ko lati koju ija si esu, o n ba fi ohun sokan ni. Ese Bibeli ti a ka ni so fun wa wipe eje Jesu ti to lati sise fun wa sugbon kii se lai si ifohunsokan re. iwo ati emi ni o ye ki a fi ohun sokan nipa fifihan ati ijeri si otito Oro Olorun ati ohun ti eje Jesu nse ti o si duro fun.
Nitorina, mu okan kuro ninu ero ibi gbogbo, awon oun ti o n ri, tabi irohin, ki o si pase ohun ti Olorun so nipa ohun naa.
Bi o ba tile je ohun ti o ni lati maa se titi, koju ija si esu. Eyi nikan ni ona ti a le fi segun awon ota ilosiwaju wa.
ADURA
Baba oke orun, ran mi lowo ki n le maa ranti lati maa fi otito re han ninu gbogbo ipenija ti mo ba n koju ni oruko Jesu. Amen
BIBELI KIKA: Genesis 11: 1-9