PURSUING HIS COUNSEL ALWAYS

PURSUING HIS COUNSEL ALWAYS

THE SEED

“The Israelites accepted some food from them, but did not consult the Lord about it.” — Joshua 9:14 (GNB)

One of the greatest mistakes believers make is assuming we can handle some matters without God’s counsel. Israel fell into this trap when they trusted their judgment instead of asking God. As a result, they made a covenant they could not undo. We must learn to seek God’s counsel in both big and small matters. Doing so helps us practice hearing His voice and builds a habit of relying on Him. When tough seasons arise, discerning His direction becomes natural because we’ve walked closely with Him daily. Never think a matter is too small to bring before God. The more we lean on Him, the wiser and more victorious our decisions will be.

Reflection: A praying heart makes fewer mistakes.

 

BIBLE READING: Joshua 9:1–21

PRAYER: Heavenly Father, I choose to seek Your counsel in all things. Guide my decisions daily, in Jesus’ name. Amen.

 

LILEPA IMORAN RE NI IGBA GBOGBO

IRUGBIN NAA:

“Àwọn ọkùnrin Israẹli sì yẹ oúnjẹ wọn wò, wọn kò sì wádìí ní ọwọ́ Olúwa.” Josua 9:14

Okan ninu awon asise nla ti onigbagbo maa n se ni ero wipe awon le dojuko awon isoro kan lai nilo imoran Olorun. Awon omo Isreali subu sinu panpe yii nigba ti won tẹ̀ si imo ara won, dipo lati beere lowo Olorun. Fun idi eyi, won da majemu ti won ko le yipada. A gbodo kọ́ lati wa imoran Olorun ninu oro aye wa boya o kere tabi o tobi. Sise eyi maa nran wa lowo lati gbo ohun Re, ati lati kọ́ iwa gbigbekele le e. Nigbati akoko inira ba dide, mímo idari Re yoo rorun nitori a ti rin pelu Re timotimo. Ma se ro wipe ohun kan kere ju lati gbe wa si iwaaju Olorun. bi a ba se ngbekele sii, bee ni ipinnu wa yoo yori si isegun si, ti yoo si mu ogbon wa.

Asaro: Okan ti ngba adura ki i se asise pupo.

 

BIBELI KIKA: Josua 9:1-21

ADURA: Baba wa orun, mo yan lati wa imoran Re ninu ohun gbogbo, to mi si ona ninu ipinu mi lojoojumo, ni oruko Jesu. Amin.

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *