SEEN BY GOD
THE SEED
“The eyes of the LORD are in every place, beholding the evil and the good.” — Proverbs 15:3 (KJV)
Nothing escapes God’s sight—our actions, motives, and private thoughts are all open before Him. This is both a comfort and a caution. He sees unnoticed faithfulness as surely as He sees hidden sin. We may deceive people, but we cannot deceive the One who searches hearts. For the righteous, God’s watchfulness assures: He does not forget your labor of love. For the unrepentant, it warns: secret sins are still public to God and will be brought to account. For all believers, it summons us to live honorably, worship sincerely, and make Spirit-led choices. In church life and leadership, this truth must shape our decisions. Preferential treatment, pride, and politics grieve the Spirit. Let God’s gaze guide us—seeking His will above appearances.
Reflection: Live today as if you could see the eyes that already see you.
BIBLE READING: Proverbs 15:3–5
PRAYER: Father, teach me to walk before You with a clean heart. Guard my motives, steady my steps, and make my life pleasing in Your sight. Amen.
OLORUN RI
IRUGBIN NAA:
Oju Oluwa mbẹ ni ibi gbogbo, o nwò awọn ẹni-buburu ati ẹni-rere. IWÉ ÒWE 15:3
Ko si ohun to pamo loju Oluwa. Ise wa, ero ikoko wa mbe ni kedere loju Oluwa. Eyi je itunu ati ibawi. O ri awon iwa otito to farasin bakannaa ni O ri awon ese ikoko. A le tan eniyan je, sugbon ako le tan eni to nse awari okan. Olorun nbojuto awon olododo, ko gbagbe isin ife yin. O kilo fun awon alaironupiwada wipe gbogbo ese ikoko, wa ni kedere niwaju Olorun, won yio si jiya ese naa. O ro gbogbo onigbagbo lati gbe igbe aye rere, sin tokantokan, ki a si je ki emi ma dari awon ipinnu ti a ba se. Ninu ile ijosin, ati didari, otito yii gbodo han ni ipinnu wa. Oju isaju, igberaga, ati ireje maa nle emi jina. E je ki oju Oluwa ma towa ki a si ma lepa ife Re.
ERO: Lo aye re loni bi enipe o ri Olorun to nwo o.
BIBELI KIKA: Owe 15:3-5
ADURA: Baba, ko mi lati rin niwaju Re pelu okan mimo. Pa erongba okan mi mo, to isise mi, ki o si je ki aye mi ki o wu O. Amin