Songs Of Praises

THE SEED
“Then sang Moses and the children of Israel this song unto the Lord, and spake, saying, I will sing unto the Lord, for He hath triumphed Gloriously: the horse and it’s riders has He thrown into the sea.” Exodus 15:1

Who is like unto thee, Oh LORD, among the gods? Who is like thee, Glorious in Holiness, fearful in praises, doing wonders? That is why the Lord should be our strength and song, He’s our salvation, He’s our God, He has prepared us an habitation. Our Father is God, we shall exalt Him. we shall sing song to Him for His Greatness and His Excellence. Thou in thy Mercy hast led forth the people which thou hast redeemed, thou hast guided them in thy Strength unto thy Holy habitation, The Lord shall reign for ever and ever. We should praise Him with the sound of the trumpet, Praise Him with the psaltery and harp, praise Him with the timbrels and dance, praise Him with stringed instruments and organs, praise Him upon the loud cymbals , praise Him upon the high sounding cymbals. Let everything that hath breath sing Praises unto God.

BIBLE READING: Exodus 15:1-7

PRAYER: May we always have reasons to praise the Lord in Jesus Name. Amen

ORIN OPE

IRUGBIN NAA
Nigbana ni Mose ati awọn ọmọ Israeli kọ orin yi si OLUWA, nwọn si sọ pe, Emi o kọrin si OLUWA, nitoriti o ti ṣegun nínú ogo: ẹṣin ati awọn ẹlẹṣin li o ti sọ sinu okun. Ekísódù 15:1 (KJV).

Tani o dabi iwọ, Oluwa, ninu awọn ọlọrun? Tani o dabi rẹ, Ologo ni mimọ, ẹru ni iyin, ti n sise iyanu? Ìdí nìyí tí o Fi ye ki o je agbára àti orin wa, Òun ni ìgbàlà wa, Òun ni Ọlorun wa, Ó ti pèsè ibùgbé fún wa. Baba wa ni Olorun, a o ma gbega. Ao ma korin si I Fun titobi ati Ola Re. Iwo ninu anu Re li o dari awon ènìyàn ti iwo ti rapada, iwo li o ti se amona won ninu Agbara Re Si ibugbe mimo, Oluwa yio joba lae ati laelae. O ye ki a yin pelú ohun elo Orin olohun gbooro, Ẹ fi ohun-elo orin ati duru yìn in, Ẹ fi ìlu ati ijó yìn in, ẹ fi ohun èlo okùn ati awọn fere yin e yin lori aro ti npariwo. Je kí gbogbo ohun tí ó ní èémí korin ìyìn sí Ọlọrun.

BIBELI KIKA: Ekísódù 15:1-7

ADURA: Jẹ ki a ni idi nigbagbogbo lati yin Oluwa ni Orukọ Jesu. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *