STAND STILL THE BATTLE IS THE LORD’S
THE SEED
“You will not need to fight in this battle. Position yourselves, stand still and see the salvation of the Lord… for the Lord is with you.” 2 Chronicles 20:17 NKJV
Some battles are not won by busier strategies but by better posture. When Judah faced a coalition of enemies, God’s plan was worship, not weaponry. As the singers led, God set ambushes; as praise rose, confusion fell on the enemy. Standing still is not doing nothing it is taking your place in faith, refusing panic, and exalting God above the threat. Make praise your warfare, obedience your strategy, and God’s presence your confidence. He fights for what belongs to Him. Shift your eyes from the problem to the Victor. When you maximize His strength and minimize your striving, you will watch salvation unfold. Your loudest weapon may be your highest praise.
BIBLE READINGS: Exodus 14:13–14; 2 Chronicles 20:14–22
PRAYER: I lift my soul to You, Lord; let me not be ashamed. Let not my enemies triumph over me. Amen.
DÚRÓ JẸ́Ẹ́ – OGUN NÁÀ TI OLÚWA NI
IRUGBIN NAA
Ẹ̀yin kò ní láti bá ogun yìí jà. Ẹ dúró ní ààyè yín; Ẹ dúró jẹ́ẹ́ kí ẹ sì rí ìgbàlà Olúwa tí yóò fi fún yín, ìwọ Juda àti Jerusalẹmu. Ẹ má ṣe bẹ̀rù; Ẹ má sì ṣe fòyà. Ẹ jáde lọ láti lọ dojúkọ wọ́n ní ọ̀la, Olúwa yóò sì wà pẹ̀lú yín.’” – 2 Kronika 20:17
Awon ogun kan wa ti a ko le bori re nipa imo ija wa bikose nipa bi a se duro. Nigba ti Juda koju awon ota to kora won jo, eto Olorun fun won ni ki won yin in, kii se nipa oun ija. Bi awon olorin se n korin, bee ni Olorun kolu awon ota won; bi iyin se n dide, beni idamu ba awon ota won. Diduro jee ko jasi aise ohunkohun – o tumo si diduro ninu igbagbo, mase mikan, ki o si gbe Olorun ga ju ihale ogun. Fi iyin se ohun ija re, ki o si fi igboran se imo re, ki o wa fi iwalaaye Olorun se igboya re. O maa n ja fun ohun to ba je tire. Yi oju re kuro lara ogun si Olusegun. Ti o ba lo agbara Rẹ̀, ti o ko si gbokanle làálàá rẹ, iwo yo ri igbala. Iyin re le je ohun ija re to ga julo.
BIBELI KIKA: Eksodu 14:13-14; 2 Kronika 20: 14-22
ADURA: Mo gbe okan mi soke si o, Olorun; Mase je ki oju o ti mi. Mase je ki awon ota mi bori mi. Amin