THE WAGES OF SOWING AND REAPING
THE SEED
“But this I say: He who sows sparingly will also reap sparingly, and he who sows bountifully will also reap bountifully.” 2 Corinthians 9:6 NKJV
Sowing and reaping is not superstition; it is God’s moral order woven into creation. We harvest in kind and in proportion to what we plant judgment returns judgment, mercy returns mercy; stinginess shrivels, generosity multiplies. Today’s choices are tomorrow’s fields.
Use the time you have to plant what heaven can bless truth, forgiveness, service, generosity, prayer. Eternity will reveal a harvest far beyond what you imagined. Sow to the Spirit, not the flesh; the first yields life, the second decay (Gal. 6:7–8). If you want a different harvest, change your seed. Start now; small faithful sowing compounded over time becomes abundance.
Plant what you want to see God will handle the increase.
BIBLE READINGS: Galatians 6:7–10
PRAYER: Lord, help me sow to righteousness and reap eternal life. Amen.
ÈRÈ TÍ Ó WÀ NÍNÚ FÍFÚRÚGBÌN ÀTI KÍKÁ
IRUGBIN NAA
Ṣùgbọ́n èyí ni mo wí pé: Ẹni tí ó bá fúnrúgbìn kín ún, kín ún ni yóò ká; ẹni tí ó bá sì fúnrúgbìn púpọ̀, púpọ̀ ni yóò ká. – 2 Corinthians 9:6
Ifurugbin ati Kika kii se igbagbo-asan; won je eto Olorun ti a se mo iseda. Awa n koore iru ati gege bi a ba se furugbin si – idajo a ma mu idajo jade, aanu yo so eso aanu; onroro yoo padanu, afunni yoo gba ilopo. Ohun ta ba se loni naa ni yoo so bi ola yoo se ri. Fi akoko re furugbin ohun ti orun yoo bukun – ani otito, idariji, isin, isoore, adura. Orun yoo fi ikore ti o koja oye re han o. Fúnrúgbìn sípa ti ẹ̀mí, mase fúnrúgbìn sípa ti ara. Ẹ̀mí yóò ká ìyè àìnípẹ̀kun, ara yóò ká ìdíbàjẹ́ (Galatia 6:7-8). Ti o ba fe ikoore ti o yato, yi irugbin re pada. O si le bere bayi; irugbin kerere ti a furugbin pelu igbagbo naa ni yo da ilopo bo pe bo ya – Oluwa yoo seto ibisi.
BIBELI KIKA: Galatia 6: 7-10
ADURA: Oluwa, ran mi lowo lati le furugbin ododo kii si kore iye ayeraye. Amin.