Stay Connected To The Source

THE SEED
“In Him was life, and the life was the light of men. And the light shines in the darkness, and the darkness did not comprehend it.” John 1: 4-5

Jesus is the light and in Him is no darkness at all. When we place a light in a dark room, it gives brightness to the room, and one can clearly find his way. A place without light is a dangerous place, and there is a chance of hurting oneself. No wonder, the first thing God spoke to a world full of darkness was “Let there be Light”, and there was light.Living in the light of God is a natural lifestyle for a true believer. The more you are in the light, the more radiation you receive to become light yourself. This requires you to stay connected to the source. You can pay your electric bills but if your appliances do not have the required connection to the source, you cannot enjoy the benefits. Jesus paid the light bill for you, but are you connected? There are distractions in the world that can keep us away from the light. We stay connected through the Word. The Word of God is the Light of God. Spend more time in it, and you will see your light shine like never before.

BIBLE READING: 1 John 1: 5-10

PRAYER: Lord Jesus, help me to constantly walk in the light of your words. Save me from any thing that wants to cut me away from the source in Jesus’ name. Amen

SO PỌ MỌ ORI̒SUN ÌMỌLÈ RẸ

IRUGBIN NAA
“Nínú rẹ̀ ni ìyè wà, ìyè yìí náà sì ni ìmọ́lẹ̀ aráyé, ìmọ́lẹ̀ náà sì ń mọ́lẹ̀ nínú òkùnkùn, òkùnkùn kò sì borí rẹ̀.” Johanu 1: 4-5

Jesu ni imọ̣le, ninu Re ko si okunkun rara. Ti a ba tan fitila si inu yara to s’okunkun, yio fi imole fun ayika naa, awon eniyan yio si ri ona won. Ibi it imole ko si, je ibi to ni ewu, ti eniyan si le fara pa. Idi niyii ti Oluwa fi pase fun aye ti o s’okunkun wipe “Je ki imole wa.”, ti imole si wa.Gbigbe ninu imole Olorun je oun to pọn dandan fun onigbagbo. Bi o ba se n duro ninu imole, bẹ̒ẹ̀ ni oo̒ ma gba agbara lati je imole funra re. O gbodo so pọ̀ mo orisun imole lati le se eyi. O le san owo ina fun ile re, sugbon ti o ko ba so awon ohun elo re mọ ina yii, ko lee ṣiṣẹ̒. Jesu ti san owo imole re, sugbon se o so pọ̀ mọ̒ọ? Awon ohun itanje aye ni ma n muni kuro ninu imole. Nipa oro Olorun ni le fi so pọ̀ mọ̒ọ. Oro Olorun si ni Imole Olorun. Tu̒bọ̀ duro ninu imole yii, imole re yio si tan geere ju atehinwa lo.

BIBELI KIKA: Johanu Kinni 1: 5-10

ADURA: Jesu Oluwa ran mi lowo lati le maa rin ninu imole oro Re nigbagbogbo. Gba mi lowo awon ohun to fe ge mi kuro lodo orisun imole mi, ni oruko Jesu. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *