Know Your Seasons

THE SEED
“He has made everything beautiful in its time. He has also set eternity in the human heart; yet no one can fathom what God has done from beginning to end” Ecclesiastes 3:11

The earth is ordered in times and seasons, each characterized by its own natural events. The sun rules the day, then surrenders to the moon at night. Throughout the year, there will be natural seasons of heat, cold (winter), rain and drought. Plants and animals understand these seasons. We as humans plan according to these seasons.God speaks through nature. A believer who doesn’t understand the voice and signs of seasons will miss out on divine agenda. There are spiritual seasons that every believer must pass through. You may find yourself in a waiting season or a pruning season or even a season of harvest. There is a purpose for each season. It is the Spirit of God that gives us intelligence to know these seasons and teach us how to live through them. In whatever season you find yourself this year, trust the God of all seasons and let Him perfect His work in you. He won’t let you down.

BIBLE READING: Psalm 19; Ecclesiastes 3: 1-14

PRAYER: Lord, help me to know my seasons and to trust that you are with me all the time. Amen

MỌ ÌGBÀ RẸ

IRUGBIN NAA
“Ó ti ṣe ohun gbogbo dáradára ní àsìkò tirẹ̀, ó sì ti fi èrò nípa ayérayé sí ọkàn ọmọ ènìyàn, síbẹ̀, wọn kò le ṣe àwárí ìdí ohun tí Ọlọ́run ti ṣe láti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin.” Oniwaasu 3:11

Olorun gbe aye kale pelu igba ati akoko, ti won si ni oun afihan won. Òrùn ni n joba osan, a si teriba fun osupa ni oru. Ninu odun, igba oru, òtútù, òjò ati ògbęlè n be. Ewéko ati eranko gbogbo ni on bowo fun awon akoko yii. Awon eniyan paapaa ma n mura gege bi akoko ba se ri.Oluwa ma n soro nipa iseda owo re. Onigbagbo ti ko ba mo ohùn tabi àmì awon igba wonyii, yio padanu ètò orun fun aye re. Gbogbo onigbagbo lo ni igba tire ti yio lakoja. O le ba ara re ni igba ti o ni lati duro, tabi igba ti a n wę o mo, tabi igba ikore. Gbogbo igba ni o si ni èrèdí tire. Emi Olorun ni si n funni ni ogbon lati mo awon igba wonyi, ti a si ma ko wa bi a se le laa koja. Ninu gbogbo igba ti o ba b’ara re lodun yii, gbekele Olorun to ni gbogbo igba, Oun yio si se asepe ise Re ni aye re. Ki yio ja o kule.

BIBELI KIKA: Orin Dafidi 19; Oniwaasu 3: 1-14

ADURA: Oluwa, ran mi lowo lati mo igba mi, ki n si gbekele o wipe iwo n be pelu mi nigbagbogbo. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *